YO/Prabhupada 0412 - Krishna Wants That This Krishna Consciousness Movement Must Be Spread



Conversation with Devotees -- April 12, 1975, Hyderabad

Prabhupāda: Anāśritaḥ karma-phalaṁ kāryaṁ karma karoti yaḥ, sa sannyāsī (BG 6.1). Anāśritaḥ kar... gbogbo eyan lofe ni awon ibajade to da fun igbadun ara re. āśritaḥ karma-phalaṁ niyen. O ti gba idaabo labe abjade toda. sugbon eni tio ba gba idaabo labe abajade ise re... ise mi ni. Karyam. Ise mi ni nitumo Karyam. Abajad re o se pataki. Mo gbodo se pelu gbogbo okan mi. lehin na abajade re o ni jomi loju. Abajade towa nibe wa lowo Krsna." Karyam:" Ise mi niyen. Guru Maharaja mi ti sobe, beena ise mi ni. koburu ti ise na ba ni aseyori tabi ti ko bani. Lori Krsna niyen wa." Eni toba sise bayi, sannyasi loje. konse ntori aso ton wo sugbon lati ise ton se. Beeni, sannyasa niyen. Karyam: " Ise mi niyen." Sa sannyāsī ca yogī ca. yogi loje, yogi t'ipo kini. Gege bi Arjuna. Arjuna o gba sannyasa. gṛhastha, jagunjagun loje. sugbon nigbato mu nipataki, karyam - " Krsna fe koja. Ko buru tin ba pa gbogbo awon ara ile mi. Mo gbodo se" - sannyasa niyen. Ni alakoko o jiyan peku Krsna pe "iru ija yi o da," pe awa fe fiku pa ebi wa, ati bayi, bayi lo. O jiyan. Sugbon lehin igba to gbo Bhagavad-gita tan osi ye wipe " Ise mi leleyi. Krsna fe kin se." Karyam. Beena botilejepe olori ile loje, jagunjagun sannyasi sini. O gba bee - karyam. "Ise mi ni" itumo Karyam. Sannyasa to daju niyen. " Krsna fe ke pin egbe imoye Krsna yi kaakiri. Beena karyam ni leleyi. Ise mi ni. Ilana Oluko mimo temi niyen. Beena mo gbodo se." Sannyasa niyen. sannyasa, iwa sannyasa. Sugbon awon ofin wa. A le gba teba fe.

olugbe India: Iyen ni nkan ton se lokan awon eyan.

Prabhupada: Ah Ninu orile-ede India, awon eyan si feran. Sannyasi le sewaasu. Bibeko, ilana fun sannyasa si wa - karyam: " sugbon ise mi soso leleyi. Otan. Agbodo ti egbe imoye Krsna yi siwaju. Ise kan soso ti mo ni leleyi. sannyasi niyen. Nitoripe Krsna si wa fu ara re, o ti bere, Sarva-dharmān parityaja mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja. Ati Caitanya Mahāprabhu, Kṛṣṇa, O sowipe, yei kṛṣṇa tattva vettha sei guru haya: "Enikeni toba mo nipa sayensi ti Krsna, guru loje." kini'se guru? Yāre dekha, tāre kaha 'kṛṣṇa'-upadeśa: (CC Madhya 7.128) " Enikeni teba pade e gbiyanu lati fun ni ilani nipa imoye Krsna." Sarva-dharmān parityaja... beena t'awa ba mu nipataki " Ise mi leleyi" - lehin na sannyasi leyin na. Otan. Sa sannyāsī. Kṛṣṇa ti jerisi, sa sannyāsī. Awon eyan o fe mu ni pataki awon ilana Krsna. Ibi India niyen. Won foan le awon nkan ton farawe Krsna. Rāmakrishna si dabi Kṛṣṇa." Iru iranu yi ti oa awon eyan. Wanti se isekuse to gaju. Dipo ton ma soro nipa Krsna wan soro nipa asiwere kan ton pe ni, Ramakrishna.

Bhāgavata: Won ni maṭha nla kan ni ilu Bhuvaneśvara. Ni ilu Bhuvaneśvara wan ni Ramakrishna matha nla kan nibe. Ile-eko Vivekananda, ile-ikawe, ile, gbogbo nkan nibi si da.

Prabhupada: Awa na lese abyi. Egbodo fi daniloju awon eyan. Kosejo pe awa fe bawon figagbaga. Sugbon eyin na le sewaasu yin nibokibi.

Arakurin olugbe India: Seyen ma sele pelu awon eyan towa ni ilu Orissa...

Prabhupada;Hm?

Arakurin olugbe India: E gbiyanju lati fi dawonlooju: rara, nkan eke niyen ati wipe ti t'awa lo daju.

Prabhupada: Rara, Ise egbe Ramakrishna yi, ise daridra-nārāyaṇa-seva niyen ati ile-iwosan. Nkan ton fi fa awon eyan niyen. Kosi nkan to daju nibe. Koseni kankan to feran imoye won. Imoye wo loni gan? Ema tie da'ra yi l'aamu. Won o jo wa loju.