YO/Prabhupada 0416 - Simply Chanting, Dancing, and Eating Nice Sweetballs, Kachori



Lecture & Initiation -- Seattle, October 20, 1968

Nitoripe egbe wa yi wulo gan, awa sin gbiyanju lati tesiwaju pelu egbe imoye Krsna yi, osi rorun gan, fun asiko tawayi. Kosejo pe afe mo boya eyin ni amuye toye. kosejo na. ounkoun teyin o ba tie ti se teletele, e wa ke orin oruko Krsna - Olorun ti fun yin l'ahon - lati to Krsna prasad yi wo, ayeye t'ife kesi gbiyanju lati je ki aye yi ni ilosiwaju Ilana to rorun gan. Ise wa niyen. Beenae pe awon eyan ko paarapo pelu egbe yi, eyin na ma ni ibajade nibe. eyin na ma ri be nkan tose se loje. pratyakṣāvagamaṁ dharmyam loje. Ninu Bhagavad-gita wa sowipe ilana imora-eni yi je nkan tale se. Nkan tale foju ri. Pratyakṣāvagamaṁ dharmyam. gege bi teyin ban jeun, o ye yin pe eyin jeun o le ye yin wipe ebi ton pa yin ti tan, o le ye yin wipe e ti l'agbara. Kosi idi fun iwe-eri. Teyin bani oye nipa ara yin, nkan to da niyen. Pratyakṣāvagamam. Nkan tele foju ri nitumo Pratyakṣa, avagamam. O le ye yin. Teyin ba sasaro, kosi besele mo teyin bani ilosowaju. Se ri bayi. Eyin kan sirorun. Eyin o le mo. Sugbon nibi, teyin ba korin Hare Krsna, ele jerisi. Moni awon akeko to po, ton fi leta to po ranse simi, bi won sen jerisi. O si da gan. Pratyakṣāvagamaṁ dharmyaṁ su-sukhaṁ kartum avyayam (BG 9.2). Ati wipe o dara lati se. E korin ke jo, ke jeun. Ki le tun fesi? (Erin) E korin, ke jo ke je awon adun, kachori. Beena su-sukham ati kartum avyayam. t'awa ban se awon ise wanyi, nkan to dara gan loje, ati avyayam. Ounkoun teba se, koba tie je nkan kekere tese fun egbe yi, ohun ini teyin niyen. Ohun ini tayeraye. Teyin base iwonba kekere... sugbon e ma duro de aye atunwa. E se tan nisin. gbogbo e. Ko fibe rorun lati se; nitorina egbiyanju lati pari e. E ma duro pe " E je kin se iwonba lori eto imora eni ni aye yi l'aye to kan ma se tan." Kini idanwo lati mo boya ati pari lori eto imora eni? Idanwo to wa ni bee ti nife Olorun, Krsna si, otan. Eyin si nife, fun enikan, sugbon teyin ba pin ife yin ife yin, pe " mo nife orile-ede yi, ife fun ololufe mi, ati tibi, mosi fe gbiyanju lati nife fun Krsna na.... " Rara. Eleyi na da, sugbon teyin ba mu ife si Krsna ni pataki, eyin ma nife fun awon nkan toku, ile aye yin asi di pipe. Ife si awon nkan toku o ni dinku. Gege b eni toni imoye Krsna, o nife fun awon ebi re ati awujo re; O nife fun awon erank, osi nife si awon kokoro, ife re si tobi gan. Nkan to da loje. Aduru ife wo leni? Ninu gbogbo nkan lesekese ti gboye ba de, ife nibe ma tan. sugbon ife si Krsna si da toje pe kole tan, ife na ma posi. Nkan to da gan loje. Eyin si nife na. O kon je wipe eti nife fun awon nkan tioye ke nife fun. Eyi pada s Krsna, teyin basi nife si Krsna, Eyin ma riwipe eti nife fun orile-ede yin, awujo re, ore re, ju bese ni teletele> Nkan to da gan leleyi.