YO/Prabhupada 0422 - Ten Offenses to Avoid while Chanting the Maha-mantra - 6 to 10



Lecture & Initiation -- Seattle, October 20, 1968

Prabhupāda: Lehin na?

Madhudviṣa: "Ikefa: Keyan ma se isekuse lori agbara aadura orin kiko yi."

Prabhupada: Beeni. Nisin lati itebomi mimo yi, lati eni lo, gbogbo ese teti se seyin ti paare. Oti tan. Nisin, nitoripe eyan le fi ipaari si awon ese aye re pelu orin kiko Hare Krsna, Iyen o wipe ke tunse: "Oh, Ma se bose wunmi, lehin na ma korin adura. Gbogbo e ma tan. Rara, beeko. Ema se bayi. Ounkoun teti se seyin ti koja. E ma tunse mo. Nisin e gbe a aye mimo. Ema se imo ako ati abo laise igbeyawo, ema moti mo, ema ta tete mo, ema jeran mo. Otan nisin. Konsepe " Oh, Mon korin adura Hare Krsna. Eje kin losi Hoteli kin jeran. " Rara. Ese nla niyen je. Ema se bayi. Koni si abajade ninu orin kiko na, teyin ban se isekuse. Tesiwaju?

Madhudvisa: " Ikejo: ka ma salaaye nipa Oruko Olorun si awon eyan ti o nigbagbo."

Prabhupada: Beeni. Alaini gbagbo, awon eyan tio ni gbagbo, pe Olorun at'Oruko je oun to gaju. Gege bi ile aye yi, oruko eyan at'eni na yato. Fun apeere kasowipe Mr. John l'oruko re. Beena tin ba kigbe " John, John, John," John lee wa nibi to jina. Kosi bo sele daaun. Sugbon oruko Olorun wa nibikibi. Gege bi amohunmaworan. Ohun to wa lori amohunmaworan wa nibi toyato. teyin ba ero na, lesekese ni aworan na ma wa ninu yara yin. tawa balese eleyi ninu ile aye yi, kilode ti kolese se ninu oruko Krsna? Lesekese teyin ba ko oruko Krsna, lesekese na ni Krsna ma wa lorin ahon yin. Beena kini yen?

Madhudvisa: Meje? " Salaaye oruko mimo si awon alainigbagbo."

Prabhupada: Beena, enikeni tio ba ni'gbagbo ninu oruko Olorun ati Olorun fun ara re, pe kosi iyato, Awon o gbodo ko awon eyan nipa ogo oruko Olorun. Agbodo gbiyayanju lati ko, sugbon ti eto na o ba lee yeee, ko yeka se itebomi mimo fun, o gbodo gba asiko die lati le ni oye na. Sugbon e gbodo ranti wipe nāma cintāmaṇiḥ kṛṣṇaś caitanya-rasa-vigrahaḥ: (CC Madhya 17.133) Krsna ati oruko Krsna kosiyato kankan. Lesekese teyin ba korin Hare Krsna, itumo re niwipe Krsna n'jo lori ahon re. E godoo se gege. gege bi eyin sen fun oluko yin ni gbobo go toba wa niwaju yin, beena ti Krsna ba wa lori ahon re, o ye ke se jeje. beena oye ke mo wipe Krsna wa nibe. Krsna wa nibikibi. Olorun wa nibikibi, sugbon koi ti ye wa. Sugbon lesekese teyin ban korin oruko mimo re, itumo re niwpe eyin mo. teyin ba ni asepo pelu Krsna ema ya si mimo. Śṛṇvatāṁ sva-kathāḥ. gege bi tawa ma ni asepo pelu ina, ara wa ma gbona, beena, teyin ba ni asepo pelu Krsna ema yasi mimo. Diedie lema ya si mimo. Koni sejo awn nkan aye yi. Ilana to wa niyen.lehin na?

Madhudviṣa: Ikejo: ka ma fi oruko mimo yi fi we awon nkan aye yi."

Prabhupāda: Beeni. Nisin awaz tinse ise yi. Koye ka rowipe nkan lasan tab'ebo lawan se nibi. Rara. Awon ebo yato si nkan tawan se. O le dabi ebo sugbon, oun to gaju lan se. O gaju gbogbo awon esin lo. Eto ile iwe giga loje. Ilana basele niiife fun Olorun. Igbagbo nitumo Esin. Sugbon kon sejo igbagbo. A wa fe mo basele nife Krsna si, tabi Olorun . Beena o gaju gbogbo awon esin lo. Kon se esin lasan. Kasowipe eyin je onigbagbo, mosii je HIndu Lesekese tin ba ku, gbogbo eto Kristeni at'esin teo ma tan. sugbon ife Olorun o ni tan. Asi tele yin lo. Ibikibi teba lo, asi teletele. teba le pari, lehin na ele pada si Krsna si Odo metalokan, kesi pari gbogbo ise teni ninu aye yi. Teyib o ba le lo, lehin na asi tele yin lo. ifowo iwontunwonsi teba ni on tan. Asi ma posi. Tesiwaju?

Madhudvisa: "Ikesan: aifetisile ninu orin kiko Olorun."

Prabhupada: Beeni. Teyin ban korin agbodo gbo. Ise sasaro loje. Hare Kṛṣṇa, awon oro meji, Hare Krsna, eyin na ma gbo. teyin ba gbo okan yin ati ahon yin ma gbokan le. Sasaro pipe niyen, yoga ti'po kini niyen je, igboran ati orin kiko. tesiwaju?

Madhudvisa: Lehin na ikewa: " Ifarasi awon nkan aye yi tawa ban korin adura yi."

Prabhupada: Beeni. Ilana to wa niwipe agbodo fi ife wa fun nkan aye yi fun Olorun. Beena oye ka gbiyanju lati dinku. Lesekese loma je. Bhaktiḥ pareśānubhavo viraktir anyatra syāt (SB 11.2.42). Teyin ba ni ife fun Olorun, lehin ife teni fun awon nkan iranu aye yi ma tan. Boseje niyen. Sugbon egbodo gbiyanju na. Nkan toma sele niyen. gege bi t'aba jeuin, ebi ton pa yin ma tan. Ti inu yi ba ti kun lehin na ema sowipe, " Mi o fe mo. Beeni, Inu mi ti kun..." Beena, imoye Krsna yi si dara toje wipe pelu ilosiwaju ninu imoye Krsna yi ema gbagbe igbadun iranu teyn ba ni ninu aye yi. teyin ba wa lori ipo yi eyin o ni fe ni nkankan se pelu iranu aye yi. Idanwo to wa niyen. Eyin o le so, " moti ni ilosiwaju ninu sasaro ti mon se, sugbon gbogbo ifarasi ti moni fun igbadun aye yi si wa boseje." Kosi ilosiwaju kankan. Itumo ilosiwaju niwipe ifarasi teni fun awon igbadun aey yi ma dinku. Ilosiwaju to wa niyen. Nisin e le korin.... Ah, eyin tini.... Ekorin Hare Krsna.