YO/Prabhupada 0423 - I am Laboring so Hard for You, But you Don't Take Advantage



Lecture on SB 2.9.14 -- Melbourne, April 13, 1972

Beena nkan to da gan loje. Aye to wa leleyi. Tawa ba l'aaye, Laksmi. Basele sise fun Krsna. Lakṣmī-sahasra-śata-sambhrama-sevyamānam (Bs. 5.29). Ti mo ban gbiyanju ninu aye yi, mole laaye lati wonu ijoba Krsna, lati ni aye to da, sugbon tin ba fisile, alailoririe nimi. teyin ba tie wo lule. Sugbon eyin si l'aaye lati tesiwwaju. Sugbon botieje wipe, eyin o le paari, beena nkan "to dara," loje, nitoripe ninu aye too kan eyin ma ni ara eda eyan. fun karmi lasan, iru ara wo loma ni ninu aye to kan? Kosi iroyin kankan. Yaṁ yaṁ vāpi smaran loke tyajaty ante kalevaram (BG 8.6). O le d'igi, tabi ko di ologbo, tabi ko d'orisa. Sugbon kole gaju awon orisa lo. Otan. tani awon orisa na je? Wan ni aaye ninu awon isogbe orun, sugbon lehin to ba tan wan si pada si aye yi. Kṣīṇe puṇye punar martya-lokaṁ viśanti. lehin igba ti owo iwontunwonsi ba tan, punya, ise rere, ba tan, wansi pada sibi. Ā-brahma-bhuvanāl lokan punar āvartino 'rjuna: " Teba tie losi Bhramaloka ibi ti Brahma n'gbe, tojepe awa gan o le siro iwonba ojo kan aye re, teba tie losibe, lehin na e tun ma pada wa." Mad-dhāma gatvā punar janma na vidyate. " Sugbon teyin ba wa s'odo mi lehin na koni sejo pe eyin ma pada sibi." Anfanni imoye Krsna niyen.

tyaktvā sva-dharmaṁ caraṇāmbujaṁ harer
bhajann apakvo 'tha patet tato yadi
yatra kva vābhadram abhūd amuṣya kiṁ
ko vārtha āpto 'bhajatāṁ sva-dharmataḥ
(SB 1.5.17)
tasyaiva hetoḥ prayateta kovido
na labhyate yad bhramatām upary-adhaḥ
tal labhyate duḥkhavad anyataḥ sukhaṁ
kālena sarvatra gabhīra-raṁhasā
(SB 1.5.18)

E gbodo ka gbogbo eleyi. Eyin o kin kaawe. Ninu apa kini Bhagavata wanti salaaye awon nkan wanyi. Sugbon mio rowipe eyin ti ka ninu iwe na. Se ti kaa? Beena teyin o ba kawe, gbogbo igba lema ni idamu: " Oh, e jekin losi orile-ede India lati Japan, tabi si Japan lati India." Eyin o ni ifoko bale nitoripe eyin o kin kawe. Mon sise gan fun yin sugbon eyin o fe gbiyanju. Ema gbiyanju fun ji jeun ati sisun. Emu awon iwe yi ni pataki, ile aye yin ma ni ilosiwaju. Ise mi - Moti fun yin ni awon nkan to dara, lat'ajo titi d'aale lati fun yin ni gbagbo, pelu gbogbo oro yi. sugbon teyin o ba mu eto na ni pataki, kini mofe se fun yin?: O daa be.