YO/Prabhupada 0449 - By Bhakti, You Can Control the Supreme Lord. That is the Only Way



Lecture on SB 7.9.3 -- Mayapur, February 17, 1977

Beena Brahma, ni eda t'alakoko ninu agbaye wa. Eru ba Laksmi, eru si ba Brahma. Nitorina Brahma bere lowo Prahlada Maharaja pe " Losi waju, omo mi, lo fokan Olorun bale. Iwo nikan lole se, nitoripe nitori e lose wa ninu irisi ton deruba gbogbo wa. Baba re ti jeki inu bi nitoripe osin fun e ni idamu, pelu iya to fi je e, pelu awon isoro to fi e si. Nitorina lose wa ninu irisi ton deruba gbogbo wa. Beena iwo nikan lole fokan re bale. Kosi basele se." Prahlāda preṣayām āsa brahma avasthita antike. Beena Prahlāda Mahārāja, toje olufokansi pataki, oun nikan lole jei okan Olorun bale. Bhaktyā, pelu bhakti nikan lele ni idari lori Olorun. Ona kan soso to wa niyen. Bhaktya mam abhijananti (BG 18.55). Lati bhakti na ni imoye yi ti wa, lati bhakti lele ni idari lori Olorun. Vedeṣu durlabham adurlabha ātmā-bhaktau. Kosi besele ni oye nipa Olorun lati kika awon Veda nikan. Vedeṣu durlabham adurlabha ātmā-bhaktau. sugbon fun awon olufokansi, Osi wa fun won. Nitorina bhakti ni orisun. Bhaktyām ekayā grāhyam. Afi lat'ona bhakti nikan lele gba, ele ba Olorun soro bi ore. Awon oluso maalu, won ba Krsna sere bi ore: Egbe wa ni Krsna je." Sugbon won nife Krsna gidi gan. amuye ton ni niyen. Nitorina nigbami Krsna asi gbe awon oluso maalu wanyi lori ejika ra. Krsna si fe pe " Awon bhakt ami.. Edi Bhakta mi ke ni idari lori mi. Gbogbo eyan lon gbadura simi pel'ogo. Mofe eni tole wa lati nidari lori mi." Nkan tofe niyen. Nitorina lose gba Iya Yasoda lati ni idari lori re. Bawo lase ni idari lori Olorun? Īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ (Bs. 5.1). Oun lo ni idari lori gbogbo nkan. Talo le nidari lori e? Kolese se. sugbon o ti gba ki awon olufokansi re to w amimo kon ni idari lori E. O ti gba, " Iya mi e ni idari lori Mi. E fokun so Mi. E f'egba han mi k'eru ba mi."

Beena gbogbo nkan lo wa n'be. Ema rowipe nkan lasan l'Olorun je, rara, śūnyavādi. Gbogbo nkan loje. Janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). Athāto brahma jijñāsā. Eyin tin sewaadi lori Brahman. Paraṁ brahma paraṁ dhāma pavitraṁ paramaṁ bhavān (BG 10.12). Ibuinu gbodo wa, konsepe Olorun gbodo wa l'alaafia nigbogbo gba. Sugbon iyato ninu ibinu re ati alafia re niwipe, ibajade kanna lon ni. Prahlāda Mahārāja, olufokansi... Inu re si dun gan si Prahlāda Mahārāja, inu si bi gan si baba re, sugbon ibajade kanna loni: awon mejeji sini'gbala. Botilejepe awon olufoakansi ma di alabasepo si Olorun, sugbon awon esu wanyi t'Olorun pa, awon o le di alabasepo si- koi ti muye to - sugbon asi wole sinu odo metalokan. Asi nigbala lati idimu aye yi. Beena kilode ti awon olufokansi ma gba ipo kanna? Nitorina māṁ eti. Tato māṁ tattvato jñātvā viśate tad-anantaram (BG 18.55). won visate, ma wole sinu odo metalokan. Gbogbo awon eyan tonri nigbala le wole.

brahma-bhūtaḥ prasannātmā
na śocati na kāṅkṣati
samaḥ sarveṣu bhūteṣu
mad-bhaktiṁ labhate...
(BG 18.54)

sugbon awon olufokansi, won ma wole sinu ijoba re, isogbe Vaikuṇṭha tabi isogbe Goloka Vṛndāvana. bayi leyan le gba ipo re. sugbon t'awa o ba gba bhakti yi, lehin na a le wole sinu ina Brahman, sugbon o daju pe ele tun pada sinu aye yi. Āruhya kṛcchreṇa paraṁ padaṁ tataḥ patanty adho 'nādṛta-yusmad-aṅghrayaḥ (SB 10.2.32). awon alainigbagbo, won le wole sinu ijoba mimo yi. Nkan ton pe ni paraṁ padaṁ. Padaṁ padaṁ yad vipadāṁ na teṣām (SB 10.14.58). sugbon awon na le pada. Āruhya kṛcchreṇa. lehin aimoye awe ati inira leyan le wole sinu ina Brahman. sugbon afi teyan ba ni iroyin nipa param padam - samāśritā ye pada pallava plavam - eyan le pada s'aye yi. Ninu ile aye yi bhūtvā bhūtvā pralīyate wa (BG 8.19).

sugbon ninu ijoba mimo, teba wole sinu ijoba mimo, latibe na nigbami odabi wipe. niotooro, ife okan Olorun niyen. gege bi Jaya-Vijaya. Awon alabasepo taya taya lon je. sugbon alaye to wa niwipe Krsna fe kon lo... Hiraṇyakaśipu..., awon mejeji, Jaya-Vijaya, kon lo sinu ile aye yi, mosi fe ba won ja." Nitoripe lati ba won ja ogbodo binu. Nibo loti fese? Ni Vaikuntha kosi bosefe binu tabi ko ba won ja. Kolese se. Nitorina lose se ki awon olufokansi re wa " E lo sinu ile aye yi ked'ota simi, bayi mole bayin ja. Inu asi bi mi," nitoripe ni Vaikuntha, ninu odo metalokan, ko saye kankan. Gbogbo eyan lon sise, ore ni gbogbo eyan je. Nibo l'ejo ija fe jade? Sugbon emi lati ja wa, ibinu yi na siwa. Nibo loti fe se? Nitorina ni Krsna se wa,, asi binu gan ati awon olufokansi na asi d'ota re, Krsa-lila leleyi, nitya-lila. Nkan ton sele niyen.

Ese pupo.

Ajo: Jaya! Haribol!