YO/Prabhupada 0451 - You Do Not Know Who is Devotee, How to Worship Him, Then We Remain Kanistha



Lecture on SB 7.9.4 -- Mayapur, February 18, 1977

Beena amuye yi loma jeke d'olufoakansi mimo, maha-bhagavata. sugbon ipo orisirisi wa. awon maha-bhagavat lati kekere lon pe ni nitya-siddha. awon siddha tayeraye lonje. Won wa fun nkan. Beena Prahlada Maharaja wa fun idi yi, pe awon esu, ati baba re, won fun ni isoro to po gan nitoripe oni imoye Krsna. itosona to wa niyen. Prahlada Maharaja si fi eleyi han pel'ase Krsna. Hiraṇyakaśipu na si wa - lati fi han basele d'ota Krsna; Prahlada Maharaja si fihan basele di olufokansi. Nkan ton sele niyen.

beena maha-bhagavata... Kaniṣṭha-adhikārī, madhyama-adhikārī ati mahā-bhāgavata, tabi uttama-adhikārī. Kaniṣṭha-adhikārī, nibere won ti ko won lati sadura si irisi Olorun dada. Pelu awon itosona sastr, pelu itosona gur, eyan gbodo ko lati sadura si awon irisi Olorun.

arcāyām eva haraye yaḥ
pūjāṁ śraddhāyehate
na tad-bhakteṣu cānyeṣu
sa bhaktaḥ prākṛtaḥ smṛtaḥ
(SB 11.2.47)

sugbon eyan gbodo tesiwaju. Ilosiwaju ise ifarafun Oluwa. sugbon taba kan duroo sori ipo adura si awon irisi, tawa o ni ife kankan fun awon elomi - na cānyeṣu na tad-bhakta - teyin o mo eni ti awon olufokansi je, besele sadura si, lehin na asi ma wa lori ipo kaniṣṭha-adhikārī. ati madhyama-adhikārī itumo re niwipe o mo ipo re ati ti awon elomi, ipo awon olufokansi, ipo Olorun, madhyama-adhikari niyen. Īśvare tad-adhīneṣu bāliśeṣu dviṣatsu ca (SB 11.2.46). Iriri merin loma ni: Bhagavān, īśvara; tad-adhīneṣu, eni toti gba idaabo Bhagavan - itumo olufokansi leleyi - īśvare tad-adhīneṣu; baliśu, awon omode lasan, gege bi awon omode, Balisa, arbhakah ati dvisatsu,, itara. Awon ton je madhyama-adhikari le ri awon eyan merin wanyo, asi bawon wi lototo. Kini yen? Prema-maitrī-kṛpopekṣā. Isvara, ife s'Olorun, Krsna,prema. ati maitri. lati s'ore nitumo Maitri. Eni toje olufokansi, agbodo s'ore pelu e. awa ogbodo ni itara, agbodo s'ore. Maitrī. gege bi awon omode tio mo nkankan, krpa- lati fi ore-ofe yi han, bi won sele d'olufokansi, bonsele korin, kon jo, e fuwon lounje, ke ko won leeko. krpa niyen. eyi to keyi, upekṣā. awon eyan toni itara lon pe ni Upekṣā, ema ni asepo pelu wo. Upeksa. sugbon maha-bhagavata, koni upeksa kankan. O si niife awon dvisatsu. Gege bi Prahlada Maharaja. Prahlāda Mahārāja, baba re si ni itara gan. Prahlada Maharaja si ko lati gba ibukun kankan fun ara re, sugbon osi bere lowo Oluwa Nrsimha-deva pe ko dariji baba re, pe " Ko bere fun nkankan fun ara re. sugbon o mope " nigbati baba mi wa laye osi huwa bi ota siyin... (isinmi) Beena aye ti wa lati bere pe ke dariji baba mi." Beena Krsna mobe. Oti dariji baba re na. nitoripe o di baba Prahlada Maharaja o ti ni ibukun yi tipe. Kon se nkan lasan lati ni iru omo-okurin to da bayi. Lesekese ti Prahlada Maharaja bere lowo Nrsimha-deva " E dakun E dariji baba mi, lesekese na lo sowipe, " Baba re ni kankan ko - baba re, baba agba re, gbogbo wa nimo ti dariji." Beena oye ka k'ogbon lati Prahlada Maharaja pe t'omode ba d'olufokansi ninu ebi, omo da daju niyen. Oun lon sise to daju fun awon ebi re. sugbon awon oniranu wanyi won ronu pe " Omo mi ti d'olufokansi. Emu wa pada p'agidi, e jigbe." Oniranu ni awon eyan je Se ri bayi? Ko ye won pe nkan ijeere nla loje pe " Omo mi ti d'Olufokansi. Gbogbo ebi mi ma ni igbala." Sugbon ko s'ogbon kankan lori won. Awon eyan yi o l'opolo. Nitorina ni mose sowipe, mio ji opolo awon eyan mon fun won l'opolo. Awon eyan wanyi o l'opolo. (Erin) Beena emu ise yi ni pataki ke se dada. Ese pupo

Ajo: Jaya!