YO/Prabhupada 0459 - Prahlada Maharaja Is One Of The Mahajanas, Authorized Persons



Lecture on SB 7.9.7 -- Mayapur, February 27, 1977

Pradyumna: Isotunmo - Prahlada Maharaja si f'okan re sori Nrsimha-deva pelu gbogbo okan re pel'okan lori re, osi bere sini gbadura pelu ife ati ohun to kere."

Prabhupada:

astauṣīd dharim ekāgra-
manasā susamāhitaḥ
prema-gadgadayā vācā
tan-nyasta-hṛdayekṣanaḥ
(SB 7.9.7)

Ilana to wa niyen. Ilana yi kole dede wa, sugbon teba gbiyanju lati sise, asi rorun, gege bi won se salaaye ninu Bhagavad-gita, man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). Eyin o le de ipo Prahlada Maharaja lesekese. Kolese se. sadhana-bhakti ni ilana t'alakoko. ipo Prahlada Maharaja ya yato. maha-bhagavata loje. Nibi topo ati ri wie nitya-siddha loje. Awon olufokan si meta lowa: nitya-siddha, sādhana-siddha, kṛpa-siddha. wanti salaaye awon nkan meta wanyi ninu iwe "Nectar of Devotion. Itumo Nitya-siddha ni awon eda ton wa pel'Olorun nigbogbo'gba. Awon lon pe ni nitya-siddha. awon sadhana-siddha lon ti wole sinu aye yi, sugbon pelu ise ninu ise ifarasi Olorun pelu awon ofin ati aimase, pelu itosona sastra, ikeeko guru, bayi, eyan le de ipo kanna pelu awon nitya-siddha. sadhana-siddha leleyi. imi tunwa. Krpa-siddha niyen. Itumo Krpa-siddha niwipe... Gege bi Nityananda Prabhu, osi fe ki Jagai-Madhai ni gbala. Kosi sadhana konkon. Awon eyan yi o tele ofin konkon. Omo odaran at'ole lonje, won si wolule gan. sugbon Nityananda Prabhu fe fihan pe, "mole fun awon aburo mejeji nigbala. lai wope won wolu le gan." Nkan ton pe ni krpa-siddha. Agbodo ranti awon ipo meta wanyi: nitya-siddha, sādhana-siddha ati kṛpa-siddha. sugbon ton ba di pipe, lat'eyikeyi ona ton ba gba, gbogbo won kon ma wa lori ipo konna.

Kosi'yato konkon Beena nitya-siddha n'ipo Prahlada Maharaja. Gaurāṅgera saṅgi gane nitya-siddha boli māne. Caitanya Mahāprabhu, nigbat'o wa.. Oun ni kon ko, sugbon awon iyoku na. Gege bi Krsn, awon olufokansi bi Arjuna to sokale wa po gan. nitya-siddha ni Arjuna je, ore nitya-siddha. Nigbati Krsna sowipe " Moti salaaye imoye Bhagavad-gita yi si orisa orun," imaṁ vivasvate yogaṁ proktavān aham avyayam (BG 4.1), aimoye odun seyin ni ti sele. Lati sewaadi oro na, Arjuna bere lowo Krsna, omo odun kanna l'awa mejeji je. Bawo lose fe kin gba wipe Iwo lo saalaye imoye yi aimoye odun seyin si orisa Orun?" Beena kini idaaun Krsna na " Arjuna mi, iwo at'Emi, ati farahan aimoye igba. Iyato to wa niwipe, o ti gbagbe. Itumo re niwipe, iwo na si wa nigbayen nitoripe ore mi nitya-siddha loje. Gbogbo'gba tinba farahan iwo na man wa pelu mi. Sugbon o ti gbagbe, mio ti gbagbe." Iyato laarin awon jiva ati (ko daju) tabi Olorun, pe iwonba kekere laje s'Olorun; nitorina lasen gbagbe. sugbon Krsna o le gbagbe. Iyatoo to wa niyen. beena nitya-siddha. nitya, mahā-bhāgavata, nitya-siddha ni Prahlada Maharaja je. awon bayi man wa lati jeki awon lila Krsna wa ni pipe. Beena kilode toye ka farawe Prahlada Maharaja. Eleyi o da. Mahājano yena gataḥ sa panthāḥ, Moti salaaye lana. Ikan ninu awon mahajana ni Prahlāda Mahārāja je, awon eda tonje olori, awon olufokansi olori. Oye ka tele. Mahājano yena gataḥ sa panthāḥ. Beena śrutayo vibhinnāḥ.

tarko 'pratiṣṭhaḥ śrutayo vibhinnā
nāsau munir yasya matam na bhinnam
dharmasya tattvaṁ nihitaṁ guhāyāṁ
mahājano yena gataḥ sa panthāḥ
(CC Madhya 17.186)

Eyin o le mo nipa Olorun pelu ogbon ori tabi'ijiyan. Kole pejo lailai. Awon Mayavadi po gan, won soro nigbogbo'gba: " tal'Olorun je?" Neti neti: eleyi ko, eleyi ko, eleyi ko. Kini Brahman?" Beena pelu ilana yi kosi besele ni oye nipa Olorun. Jñāne prayāse udapāsya namanta eva. Caitanya Mahāprabhu ti gba fomula yi. Pelu imoye, pelu ikeeko yin, teyin ba fe ni oye na - ele je alakowe giga - sugbon kole ran yin lowo lati mo nipa Olorun. Amuye yin ko niyen. Eyin gbodo fi igberaga yin sile pe " Olowo nimi," " alakowe nimi," "Mo lewa gan", ati bayi bayi lo. janmaiśvarya śruta śrī (SB 1.8.26) ni gbogbo e. Amuye gidi ko leleyi je. Kuntīdevī ti sowipe, akincana gocaraḥ: "Kṛṣṇa, akiñcana gocara loje." Akiñcana. Enikeni to ban rowipe " emi ni moni nkan bayi bayi" itumoo Kincana niyen; nitorina mole ra Krsna," Oh, rara, beeko. Kolese se. Egbodo resile, akincana-gocarah.