YO/Prabhupada 0462 - Vaisnava Aparadha is a Great Offense



Lecture on SB 7.9.7 -- Mayapur, February 27, 1977

Prabhupāda: Ese nla ni Vaiṣṇava aparādha. Se mo Ambarīṣa Mahārāja. Olufokansi loje, Durvāsā, si ni igberaga nitori agbara idan(yogi) to ni osi see Ambarisa Maharaja, Krsna si fiyaje pelu sudarśana-cakra to ranwa. osi bere iranlowo lati awon eyan to po - Brahma, Visnu. O si le lo si Visnuloka, sugbon won o dariji. Osi pada wa ba Vaisnava, Ambarīṣa Mahārāja, to doobale fun. sugbon Vaisnava na si dariji lesekese. Beena asise nla ni Vaiṣṇava aparādha yi je, hātī-mātā. Beena agbodo se jeje ka ma se awon Vaisnava aparadha. awa ogbodo.. Arcye viṣṇu śilā-dhīr guruṣu nara-matir vaiṣṇava-jāti-buddhiḥ (Padma Purāṇa). Asise imi ni vaiṣṇava-jāti-buddhiḥ, asise nla. Beena, lati rowipe eyan lasan ni guru je, asise nla na niyen. lati rowipe awon irisi Olorun pe latii irin, okuta lonti wa.. asise nlan na niyen. Sa nārakī.

Beena agbodo se jeje pelu awon ofin wanyi, kasi tele ilana awon Vaisnava. Mahājano yena sa gataḥ. Ema rowipe omode lasan ni Prahlāda Mahārāja je. Agbodo ko lati Prahlāda Mahārāja lati ni ilosiwaju ninu ise ifarasi Olorun.

Ese pupo.

Ajo: Jaya Prabhupada.