YO/Prabhupada 0475 - We Shudder as Soon as we Hear That we Have to Become Servant of God



Lecture -- Seattle, October 7, 1968

Awa o le d'eda to gaju. Awa o riri ninu awon iwe mimo, pe eda lasan ti l'agbara bi Olorun. Rara. Kolese se. Alagbara l'Olorun. Nigbogbo'gba. Teyin ba tie nigbala lowo idimu ile aye yi, Oun l'eda to lagbara ju. Nitorina l'ese iwe yi se sowipe, govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi. Ibasepo wa pelu Olorun ni, lati s'adura si, tabi lati sise fun. ISe yi dara gan. Lesekese t'aba soro nipa ise, ale bere sini rowipe "Oh, awa n'fiya je ara wa pelu ise yi." gege bi omo-okurin tobi l'ojo to koja pe " Kilode tasen dobaale?" Mio mo boya o wa nibi. Lati dobaale fun eyan kon se nkan to buru, sugobn nitoripe awa ti wa ninu ipo to yato, lati teriba fun elomi nisin inira loje. Gege bi koseni tofe gbekele orile-ede imi, koseni tofe gbekele elomi. Gbogbo wa lafe sen nkan tafe, nitoripe ile aye je iyi sodi odo metalokan. sugbon ninu odo metalokan , egbodoo teriba, teba sise si, beena ni inu yin ma dun si. Inu yin ma dun. sugbon awa o ni imoye kankan lasiko tawayi. Awa o ni ero mimo kankan, kosi ilaju mimo kankan; nitorina lojepe lesekese taba gbo nipa awon eto pe oyekadi iranse Olorun awa ma gbokan wa kuro. sugbon kosejo pe awa o fe gbo. Nkan to dara ni lati iranse Olorun. eyin ti awon oniwaasu to po toti wa, won sise fun ise Oluwa, sugbon awon eyan sin teriba fun won. Beena lati d'iranse fun Oluwa, nkan kekere ko loje. Nkan tose pataki ju loje. Govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi. Sugbon ema gba bee. Nialakoko egbiyanju lati ni oye re na. Nitorina ni Vedanta-sutra se sowipe, athāto brahma jijñāsā. E gbiyanju lati ni oye nipa Brahman. ( ariwo lati gbohun gbohun) kikode ti'ariwo yi se wa? E gbiyanju lati ni oye nipa Brahman e gbiyanju lati ni oye nipa asepo yin. lehin na leyin ma teriba, idunu teyin ma ni ma po gan, to kun pelu imoye.

wan ti salaaye dada ninu ikeeko Oluwa Caitanya. Ninu Bhagavad-gita na, ikeeko kanna lowa nibe, sugbon.. Awa sini iwe mejeji t'ati teejade, ikan Bhagavad-gita gege boseje; ikeji, Ikeeko Oluwa Caitanya. Beena Bhagavad-gita si le ko wa lati teriba. Sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). " E teriba fun mi," nkan t'Olorun so niyen. awon ikeeko Olorun, ikeeo Caitanya Mahaprabhu ni basele teriba. nitoripe o ti mo wa lara, lasiko tawayi lati mafe teriba. Orisirisi egbe lowa pelu "ero" orisirisi, ofin pataki ninu gbogbo won niwipe " Kilode ti mofe teriba?" Aisan pataki to wa niyen. Gbogbo aw egbe oselu, gege bi egbe awon kommunisti... Iyipo won si awon olori giga niwipe "kilode toye ka... Nibikibi, nkankana loje, "Kilode toye ka teriba?" Sugbon a gbodo teriba. Ipo aye wa niyen. Teyin o ba teriba fun ijoba kan, tabi awujo kan tabi nkan, sugbon leyin gbogbo e moti teriba tan. Moti teriba si awon ofin aye yi. Kosejo nipa ominiran. Mo gbodo teriba T'iku ba de, lesekese nimo gbodo teriba Awon nkan bayi to po. O gbodo ye wa. brahma-jijnasa leleyi pe " kilode ton se teriba?" Ti mio bafe teriba, won ma f'agidi fi se kin teriba. Ninu ipinle na, ti mio ba tele awon ofin ipinle na, Olori ipinle na asi fi awon olopa tabi jagunjagun fi jekin teriba pel'agidi. Beena, mio fe ku sugbon iku si ma mumi p'alagidi Mio fe d'arugbp sugon awon agbara iseda ma jekin darugbo. Mio fe ni aisan kankan, sugbon awon agbara iseda asi funmi l'aisan. Beena ilana lati teriba wanyi si wa. Nisin agbodo gbiyanju lati kilode tose je bayi. Itumo re niwipe iwa adayeba ni funmi lati teriba, sugbon isoro towa nisin niwipe awa ti teriba fun eda tio ye ka teriba fun. Nigbat'awa ba ni oye wipe agodo teriba fun Oluwa, lehin na ipo mi ma daju. Ominiran timo ni leleyi.