YO/Prabhupada 0483 - How You Can Think of Krishna Unless You Develop Love for Krishna?



Lecture -- Seattle, October 18, 1968

Beena teyin ba ronu nipa Krsna, ilana to wa niyen, imoye Krsna. lehin na mayy āsakta-manāḥ pārtha yogaṁ yuñjan mad-āśrayaḥ, teyin ba se ilana yoga yi, imoye Krsna, bawo? Mad-āśrayaḥ. "teyin ba mu idaabo eni to wa pelu mi." Mad-āśrayaḥ Mad-āśrayaḥ. towa pelu re nitumo Mad-āśrayaḥ. eyin wa pelu re lesekese teba ronu nipa re, irisi re. sugbon afi teyin ba ni idaabo oluko mimo to mo nipa re, eyin o le fokan le fun igba to po. Fun igba die loje. Nitorina egbodo lateni to mo nipa Krsna. Lehin na lema le fokan le Krsna. Egbodo sise gege toba se sofun yin. Egbodo gbe ile aye yin lori awon itosona oluko mimo. Lehin na ele tesiwaju pelu ilana yoga yi dada. Iru yoga wo niyen? Yoga ton juwe ninu Bhagavad-gita, ninu apa efa, ese iwe to kehin. Yoginām api sarveṣāṁ mad-gatenāntarātmanā: (BG 6.47) " Eni toba n'sise fun mi." mad-gata, " Ipo kini lowa." Wan ti salaaye nibi to po gan. Premāñjana-cchurita. Bawo lese fe ronu nipa Krsna afi teba nife fun Krsna? gege bi Rādhārāṇī. Rādhārāṇī, ti wa Osi loko, pelu ebi re, sugbon o si wa lati sadura si Krsna. Beena, agbodo fi Krsna s'okan wa, kabale ranti re. Lehin na ilana yi, mayy āsakta-manāḥ pārtha yogaṁ yuñjan mad-āśrayaḥ, " laabe idaabo mi, tabi awon alabasepo mi, nigbateyin ba ni oye nipa samagram, lehin na ile aye yin ma ni ilosiwaju." Asaṁśayam: " laisi iseyemeji." Kon sepe nitoripe Oluko mimo yin sowipe " Krsna l'Olorun." Rara. Teyin ba ni ibeere kankan, e beere, ke gbiyanju latgi ni oye re. Otooroo loje pe Eledumare loje, Sugbon teyin ba ni ibeere kankan, e beere. Asaṁśayam. Bayi lese le keeko ilana yoga yi, Imoye Krsna ni yoga to gaju ninu gbogbo yoga to wa, asaṁśayam samagraṁ māṁ yathā jñāsyasi (BG 7.1), lehin na ema ni oye nipa Krsna, tabi Olorun, dada, laisi iseyemeji kankan, lehin na ile aye yin ma ni ilosiwaju Ese pupo. ( awon olufokansi teriba)