YO/Prabhupada 0488 - Where is the Fighting? If you Love God, then you Love Everyone. That is the Sign



Lecture -- Seattle, October 18, 1968

Prabhupāda: Beeni.

Upendra: Prabhupāda, nigbami iyato po gan wa, laarin nkan tife Oluwa je fun awon onigbabo ati musluman, Musluman ati Buddhist, Buddhist, Hindu. Nigbami won le jiyan nipa ife Oluwa yi.

Prabhupada: Won ja, awon eyan tio nife Oluwa lon ja. Nitoripe ologbo at'aja lonje. Kosi beyin sefe ni ipo alafia laarin awon ologbo at'aja. Won gbodo ja. Beena ounkoun toba je, ija yi ma, itumo re niwipe awon eyan wanyi o si lori ipo pipe. Nibo ni ija na wa? Teyin ba nife Oluwa ema nife gbogbo eda. Aami to wa niyen Samaḥ sarveṣu bhūteṣu mad-bhaktiṁ labhate parām (BG 18.54). lehin igba teyin bade ipo idogba yi, lehin na lele wole sinu odo metalokan Oluwa. Sugbon, eyin gbodo jade. Gege bi tebafe wole si ile-iwe giga, e gbodo jade lati ile-iwe akobere, beena ketole wole sinu ipo ise ifarasi Oluwa, egbodo mo wipe gbogbo awon eda wa lori kanna Ilaju leleyi. Kosi besele se isasoto pe " Elei kekre", " Eleyi gaju" Rara. Paṇḍitāḥ sama-darśinaḥ (BG 5.18). Teyan bati kogbon dada koni se iyato kankan mo, pe " Eda eyan leleyi, maalu leleyi, aja leleyi." Asi riwipe emi mimo lowa ninu awon aso ototo wanyi. Otan. Nkan ton ri niyen, gbogbo nkan lori ipo kanna. Eyin o le sowipe awo aja tabi maalu o l'eemi. Bawo lesele sowipe kos'emi ninu won? Aisi ogbon yin niyen. Kini aami emi? Eyin na ma ri awon aami aye yi ninu eda eyan, ninu awon kokoro gan. Bawo lesele sowipe awon eda kekere, awon eranko kekere pe kos'aye ninu won? aini imoye yn leleyi. Awon igi, gan won l'emi. Beena agbodo keeko dada. Beena ife Oluwa lori imoye to daju nife Oluwa gidi. bibeko eléròkerò loje. beena awon eléròkerò , won le ja. Sugobn ife Oluwa ko niyen. niotooro, o le gan lati wa sori ipo yi, sugobn agbodo gbiyanju. Imoye Krsna niyen. Akeko ni gbogbo wa. Asi gbiuanju. sugbon ipo orisirisi lowa na. gege bi ile-iwe kilasi kewa, keje, karun kefa, ati bayi bayi lowa. pelu yoga, gege bi abaguke loje Beena ipo orisirisi lowa fun ipo pipe yi. Ipo to gaju ni onitoun ton ronu nipa Krsna. yoginām api sarveṣāṁ mad-gatenāntarātmanā śraddhāvān bhajate... (BG 6.47). Ipo to gaju ni Krsna, ironu nipa Krsna nigbogbo'gba ati Rādhārāṇī. Ipo to gaju leleyi. Koni ise imi ju lati ronu nipa Krsna.