YO/Prabhupada 0493 - When this Gross Body is Resting, the Subtle Body is Working



Lecture on BG 2.14 -- Germany, June 21, 1974

Oyewa taba rorun die wipe, ara mi konimi, ninu aye yi gan... Ni ale masi gba ara imi toyato. Mon laala. Ninu alaa na mole ri ekun. Mo losinu aginju, mosi ri ekun nibe tofe pa mi. Lehin masi bere sini sukun. Tabi, nigbami mole loba ololufe kan, okurin tab'obirin. Asin farawa mora, sugbon lori ara wa awon nkan wanyi sin sele. Bibeko kilode ti mo sen sukun? Kilode ti irúgbìnirú-ômô sen jade? lara mi? Beena awon eyan o mo wipe moti kuro ninu ara eda yi, pe moti wole sinu ara imi t'awa o le foju ri. Ara tan juwe yi wa n'be, konsejo pe owa ninu wa. won ti to ara jo. gege bi ara wa se wa ninu aso ati aso awoleke, beena ara tale foju ri yi ni aso awoleke yi, ara t'awa o le ri ni aso lasan. Beena ti ara tan foju ri yi ban simi, ara wa teyin o le foju ri n'sise. Kole ye awon okunrin didinrin wipe: " Mowa ninu ara eda, boya eyi tale foju ri tabi eyi t'awa o le foju ri." Eyan toje elese, kole ni ara t'awa le foju ri. Asi duru sinu ara emi yi tawa o le foju ri, nkan ton pe ni ëmí iwin òkú. Boya eti gbo nipa e. Imi ninu yin ti ri won. Awon iwin wanyi wa. Itunmo iwin niwipe ese eda yi ti poju tojepe kole ri ara eda gba. Kole ni ara tale foju ri. Nitorina ninu awon ilana Veda won ni ayeye ton pe ni sraddha. Ti baba eyan tabi ebi re ba ku, pelu ayeye na ole ri ara eda gidi gba. Ilana awon Veda niyen.

Beena, ole yewa wipe " Nigbami mole wa ninu ara eda yi, nigbami mole wa ninu ara emi teyan o le foju lasan wo. Beena mowa nibe, boya ninu ara tale foju ri tabi ninu ara emi tawa o e foju lasan wo. Beena eda tayeraye nimi. Sugbon tinba n'sise pelu ara emi tio se ri, ma gbagbe ara eda lasan yi. tinban sise na pel'ara eda yi, masi gbagbe nipa ara emi yi. Beena tin ba gba ara eda yi tabi ara emi na, mo wa tayeraye. Eda tayeraye nimi. Nisin isoro towa ni basele fi ara lasan at'ara emi yi sile. Isoro to wa niyen. Itumo re niwipe teyin ba wa ninu ara t'alakoko yi, ara emi, teyin o wa mo sinu ara eda lasan yi, ile aye tayeraye niyen. Nkan toye ka ri-gba niyen. Ibukin ni ile aye eda yi je si wa lat'Oluwa. Nisin o daju pe idunu ati ibanuje kon yipo ninu aye re, won sin f'agidi fun yin ni ara eda lasan ati ara emi. orisun gbogbo inira ati igbadun teyin ni leleyi. teyin ba jade kuro ninu ara eda yi, te duro sinu ara emi yin t'alakoko, lehin na eyin ma bo lowo awon inira atu igbadun wanyi. Nkan ton pe ni mukti leleyi. Mukti. oro ede Sanskrit leleyi. Igbala nitumo Mukti, koni s'ara eda lasan yi o, koi si ara eda emi yi mo. Sugbon eyin ma wa ninu ara eda mimo yin. Nkan ton pe ni mukti niyen. Itumo Mukti ni.... Wanti salaaye ninu Bhāgavatam, muktir hitvā anyathā rūpaṁ sva-rūpeṇa vyavasthitiḥ. mukti niyen. Anyathā rūpam.