YO/Prabhupada 0500 - You Cannot Become Permanently Happy in this Material World



Lecture on BG 2.15 -- Hyderabad, November 21, 1972

Prabhupāda: Teyin bafe idunnu gidi, teyin bafe idunnu to daju, lehin na egbiyanju lati ni imoye Krsna. Lehin na ema ni idunnu to daju. Bibeeko, awon nkan aye yi ma funyin ni idamu,

nāsato vidyate bhāvo
nābhāvo vidyate sataḥ
ubhayor api dṛṣṭo 'ntas
tv anayos tattva-darśibhiḥ
(BG 2.16)

Tattva-darśibhiḥ, awon eyan ton ti ri otitio to gaju, tabi awon ton ti ni imoye nipa otito to gaju, wonti jeerisi pe oro yi o ni igbese aye tayeraye, emi wa o le paari. Awon nkan meji wanyi gbodo ye wa. Ohun aye yi nitumo Asataḥ. Asataḥ Nāsato vidyate bhāvaḥ. Asataḥ, gbogbo nkan asat... Ounkoun ninu aye yi toje asat, nkan tio ni wa laaye mo, to wa fun igba die Asat. Beena eyin o le duro de idunnu tio ni tan ninu ile aye to wa fun igba die. Kolese se. Sugbon won fe ni idunnu. Orisirisi eto ton daale, Sugbon ni otooro kosi idunnu kankan. Beena gbogbo ise ton daale.. Tattva-darśī, won mo..... Tattva-darśī, eyan ti ri tabi oti ni ijerisi otito to gaju yi, o mowipe ninu aye yi kolesi idunnu kankan. ìṣoníṣókí toye ka se leleyi. Gege bi ala leleyi, teyin ba fe ni idunnu ninu aye yi. sugbon awon eyan ti ya didinrin, lasiko tawayi nipataki, won kon s'eto ninu ile aye, bonsele ni idunnu. Awa ti jeerisi fun ara wa. Kilo wa ninu orile-ede wa? Awa jina seyin lori eto ilosiwaju ninu eto ilaju. Ni orile-ede America won ni awon oko to po. Gbogbo awon okurin nibe won wa moto. Talaka niwa, sannyasis, brahmacari. Beena, ninu gbogbo awon ile-ajosin wa awa sini bi oko merin si marun. Awon oko to da gan. Awon oko wanyi gan awon ton je alakoso ninu ile isofin gan, won o ri'iru e ri. Seyin ti re bayi? Awon oko to da gan. Beena awon ena si ni awon oko to da. Sugbon isoro to wa niwipe nigbogbo'gba lon ko awon titi, afa, ikan lehin ikeji, ikan leyin ikeji,.. Oti de ipo yi, merin, marun. Merin- marun- ile oke. ( Erin) Bawo ni inu yin se fe dunsin? Nitorina tattva-darsibhih na asatah. Kosi beyin sefe ni idunnu to ma wa titi lailai ninu aye yi. Kolese se. Beena ema lo asiko yin ni ilokulo lati ni idunnu nibi. Nibo mi won sowipe, padaṁ padaṁ yad vipadāṁ na teṣām (SB 10.14.58). A le lo apeere kanna. Ni America aimoye awon eyan ti oko-moto n'kolu ton pa won. Meelo? Bawo lonse po to? Eyin o le ranti?

Śyāmasundara: ọkẹ́ kán lona meta, nkan ti mo ro niyen.

Prabhupada: ọkẹ́ kán lona meta? Rara, rara. O ju bayi lo.... Awon eyan ti oko-moto ti pa po gan. Beena imi ninu awon akeeko wa na si ku lai pe yi ni osu tokoja lati oko-moto to kolu won. Awon iku lati asise oko-moto ton kolu awon eyan ni America, ko jomi loju rara. Nitoripe awon oko-moto yi sin sare to jepe oko kan soso nikan ko, ikan si ikeji, aimoye. teyin ba si rin diedie, lesekese ( juwe ohun oko ton kolu nkan) " takar tak".