YO/Prabhupada 0515 - You Cannot be Happy, Sir, So Long you Have Got this Material Body



Lecture on BG 2.25 -- London, August 28, 1973

ale roju repete nipa aye wa. sugbon kosi bi inu yin sefe dunsi, teba si ni ara eda yi. oto oro niyen. Janma-mṛtyu-jarā-vyādhi-duḥkha-doṣānudarśanam (BG 13.9). nitorina awon eyan tologbon.. Krsna ti fun gbogbo eyan logbon; " Ode yi, seyin o riwipe ewa ninu ara eda. awujo teni ko niyi. Awujo awon asiwere loje". nkan towa niwipe,

yaṁ hi na vyathayanty ete
puruṣaṁ puruṣarṣabha
sama-duḥkha-sukhaṁ dhīraṁ
so 'mṛtatvāya kalpate
(BG 2.15)

isoro teni niwipe bawo lesele pada si ipo yin bi eda ayeraye. nitoripe eda ayeraye laje, sugbon bakanna tabi keji ati bosinu ile-aye yi. Nitorina agbudo ni ibimo ati iku. gege na isoro tawa ni basel pada si ipo ayeraye tani teletele. amṛtatva niyen, sugbon awon asiwere wanyi o mo wipe eyan le di eda tio leku. taba si gbiyanju lati monipa Krsna a le de ipo na. Janma karma ca me divyaṁ yo jānāti tattvataḥ (BG 4.9). Egbiyanju ke mo nipa Krsna, tani Krsna je. tyaktvā dehaṁ punar janma naiti (BG 4.9). Teyin o ba le sise fun krsna, egbiyanju ke mo nipa re. teba sise fun, etini gbala niyen. teba si gbiyanju lati ni oye nipa krsna sugbon awon mūḍha, asiwere wanyi wan sowipe: Ale gba wipe eyan pataki ni Krsna je, sugbon awa o le gba pe Olorun ni". Nkan ti awon Arya-samaji a so niyen. Ko buro, teba gba wipe eyan pataki loje, kilode teyin o se fe gba awon nkan to ko. huh? iru igbagbo wo niyen? Teba gba pe eyan pataki ni Krsna je, oyeke gbiyanju lati tele awon ilana ti Krsna funwa. Sugbon awon eyan yi o ni se. sugbon wansi pe ara wan ni Arya-samaj. Egbe toni ilosiwaju gan. Sugbon egbe toni iloseyin lon je. awon eyan tonni egbe toni ilosiwaju gidi ni awon elesin Krsna. Aryan niwan je. Gege bi Arjun tio fe gba awon ilana Krsna, Oga, mio le jagun, " osi sowipe anārya-juṣṭam. Enikeni toba ṣaigbọransi awon ilana Krsna, anaryan loje. enikeni toba gboran si ilana Krsna ,onitoun ni Aryan. Iyato to wa niiyen. Nitorina awon Arya-samaj, n'se aigbọransi ilana Krsan, sugbon wanfe ki awon eyan pe wan ni Aryan. Sugbon anaryan lonje. Anārya-juṣṭam. wanti salaaye awon oroyi ninu Bhagavad-gītā.

nānuśocitum arhasi. Krsna si sowipe, eda ayeraye leje. Lati de ipo togaju yi ni'se teyin ni, ara eda teni yi, igba die loma wa fun, antavanta ime dehāḥ, kilode teyin sen seto ara yi? Iyato laarin awujo Veda niyen, Awujo Aryan. Awujo Veda nitumo Aryan awon ton feran ara wan, awujo anaryan lonje, Ile-aye toyasi mimo nitumo awujo awon Aryan, basele ni ilosiwaju ninu eto mimo. Awujo gidi towa niyen. Awon eyan ton feran igbadun ara, anaryan niwan. nānuśocitum arhasi: " Ema sukun lori awon nkan aye yi"

Ese pupo. Hare Krsna.