YO/Prabhupada 0516 - You Can Attain a Life of Freedom - This is not Story or Fiction



Lecture on BG 7.1 -- Los Angeles, December 2, 1968

Prabhupāda: Govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi (Bs. 5.29).

Elesin: Govindam ādi-puruṣaṁ tam ahaṁ bhajāmi.

Prabhupāda: Awan s'aduro si Olorun Govinda. Ise wa niyen. kini abajade teyan ba s'adura si Govinda? Gege bi awon eyan ton seto lati losi Osupa. Tonba tie debe kosi nkan tonle fi se, nitoripe awon oni sayensi sowipe otutu to wan'be si po gan, bi yinyin lo je. osi rorun gan lati faram otutu towa ninu agbye wa, bawo lasefe faramo eyi towa lori osupa? sugbon planeti osupa lo sumo wa ju. Aimoye planeti to wa na, awon oni sayensi gan sowipe lati de planeti to gaju odun Ọkẹ-Meji loma gba lati debe. talo ma gbe ninu aye yi fun asiko bayi lati losibe kotun pada wa?

Awon isoro tani leleyi, nitorina lonse pe wani awon eda aye-yi gbogbo ise wa loni'soro, kosi eyi to rorun ninu e. sugbon e le gbe aye to si rorun, aye to kun fun agbara, idunnu, alaafia. oṣeeṣe. itan koleleyi. Orisiri planeti lowa ninu agbaye yi. asi ni oko ofurufu to po, sugbon lati de planeti to summon wa ju si lee gan. awasi kere gan. Taba si gbadura si Govinda, ole sese. Ele losi bikibi teba fe. ati salaaye gbogbo eleyi ninu iwe kekere wa, iri-ajo to rorun si awon planeti mi. Oseese. ema rowipe kosi bomi afi ibi tawayi. aimoye awon planeti to da gan to wa. wansi ni igbadun, ati idunnu to jutawa lo gan bawo lasele se na?

masi ka lati ese-kesan ninu iwe Bhagavad-gītā, ti Govinda salaye fun ara re, ese-kesan, Bhagavad-gītā. Oluwa Krsna sowipe,

mayy āsakta-manāḥ pārtha
yogaṁ yuñjan mad-āśrayaḥ
asaṁśayaṁ samagraṁ māṁ
yathā jñāsyasi tac chṛṇu
(BG 7.1)

wanti funwa nitumo oro yogam iru yoga wo ni Krsna fe ka se? Mayy āsakta-manāḥ. Egbokan le Krsna , iru yoga toyeka se niyen. Yoga ni imoye Krsna yi je fun wa. ni aye isin awon eyan ton se yoga, wan f'okan le nkan ti awon gan o le ri, nkan to wa lati okan wa. Sugbon oye kan f'okan le nkan sugbon tawa ba je ji nkanna wa laisi irisi, om ale gan lati f'okan si. Wanti salaaye ninu Bhagavad-gītā ninu ese kejila: kleśo 'dhikataras teṣām avyaktāsakta-cetasām (BG 12.5). awon eyan tonfe gbokan le nkan tioni irisi, isoro wan si leju awon eyan ton gbokan le oluwa. wanti salaaye. Kilode? Avyaktā hi gatir duḥkhaṁ dehavadbhir avāpyate. kosi basele gbokan le nkan tion irisi. teyin ban ronu nipa ore kan teni, tabi iya yin ati mama yin tabi eni tebaferan, ele ronu lotiti fun wakati si wakati sugbon tio ba si nkankan tele f'okan le, oma le gan. sugon wan ko awon eyan lati gbokan le oun tio si.