YO/Prabhupada 0520 - We are Chanting, We are Hearing, We are Dancing, We're Enjoying. Why?



Lecture on BG 7.1 -- Los Angeles, December 2, 1968

dhama Krsna leleyi nitoripe oun ni onihun gbogbo nkan aye yi. Koseni to je olori nibi. Anfanni pe awa lani ile-yi, America, Iro ni gbogbo e. Eyin koleni, koseni toni. Gege bi odun die to koja, bi odun ogorun merin, awon Indian pupa lonnibi, sugbon bakanna tabi keji eti gba ile yi. talo sowipe elomi o le wa gba ile yi lowo yin? anfanni iranu nigbogbo eleyi. Krsna ni onihun gbogbo nkan. Krsna sowipe sarva-loka-maheśvaram: (BG 5.29) " Emi ni Olori togaju, Oludari gbogbo awon planeti". Gege na oun loni gbogbo nkan. Ti Krsna basowipe oun ni Onihun gbogbo nkan aye yi. iyen wipe gbogbo ile-aye yi ni dhama re. kilode tefe se iyipada nibi? sugon osiwipe yad gatvā na nivartante tad dhāma paramam (BG 15.6). Olori ni itumo Paramam ninu dhama yi na, dhama Krsna sini gbogbo wan, awon planeti Krsna. Sugbon parama ko nibi. Isoro to po wa nibi. gege bi ibimo, iku, aisan ati ojo-ori arugbo. sugbon teba pada si ijoba re Goloka Vṛndāvana, cintāmaṇi-dhāma (Bs. 5.29), ele gbe nibe fun ayeraye, pelu imoye to gaju, ati alaafia to gaju.

bawo lasele debe? Krsna sowipe mayy āsakta-manāḥ: Ejeki ifarasi Krsna teni posi. Ilana to rorun. gbogbo orin tan ko, gbogbo oro yi tna gbo, gbogbo ijo tan jo, kinidi fun gbogbo e? lati le bolowo gbogbo iranu aye yi kasi faramo Krsna. Ilana to wa niyen. Imoye Krsna Egbudo fokan si nkan teba fe ronu nipa nkan na. sugbon teba gbokan le nkan iranu, nkankanna loma sele, janma-mṛtyu-jarā-vyādhi (BG 13.9), ibimo, iku, ojo-arugbo,aisan. Egudo jiya. Egudo jiya Sayensi yin,.. Koseni tole fun wa lona abajade ninu gbogbo ijiya wanyi. sugbon teba fe ona-abayo to daju, egbokan le Krsna. Ilana to rorun. Mayy āsakta-manāḥ pārtha yogaṁ yuñjan. yoga to gaju leleyi. gbogbo awon yoga to ku le funyin ni iranlowo lati de ipo imoye Krsna, sugbon teyin o ba le bosi ipo imoye Krsna, koni sidi fun gbogbo isoro wanyi. Kolesese. teba gba ona yoga tio yara, kolese se ninu asiko tawayi. Asiko yi nikan ko, ni odun ẹgbẹ́ẹdọ́gbọ̀n to koja gan kolese se. Ele takiti besefe sugbon kole si ilosiwaju ninu gbogbo nkan teyin se. Ilana yoga yi gege bi Krsna se salaaye ninu apa to kehin.. apa kesan leleyi. Ninu apa kefa, Osi soro nipa nkankanna, yoginām api sarveṣām: (BG 6.47) " Yogi to gaju ni enito le fokan le mi, Krsna". Imoye Krsna niyen.