YO/Prabhupada 0526 - If we Catch Krishna very Strongly, Maya Cannot do Anything



Lecture on BG 7.1 -- Los Angeles, December 2, 1968

Tamāla Kṛṣṇa: Ti maya ba diwamu, bawo lasele pada si Krsna?

Prabhupāda: Oh, seyen Kṛṣṇa, Kṛṣṇa ti maya ban fayin mora, egbadura si Krsna, " Edakun egbamila. Edakun Egbami la". Ona soso too wa niyen. Asi fun yin ni iranlowo. Awa ninu ijoba Maya, nitorina maya lagbara gan, sugbon taba dimo Krsna, kosi nkankan ti maya lese. agbudo foju si basefe dimo Krsna dada. Koni si oro pe eyan wolule. Beeni.

Madhudviṣa: Prabhupāda, ta ban jo lori saṅkīrtana, tan korin, bawo lasele pe awon eyan kon bawa korin na? bawo loye kase...

Prabhupada: Ekorin, ona to daju niyen. Lati fun awon eyan ni itelorun koni ise teyin se. lati fun Krsna ni itelorun ni'ise toye kese, lesekese ni awon eyan ma ni idunnu. Ati fun awon ni itelorun koni ise tawani. Awa fe funwan ni nkan, Krsna. egbudo lati funwan ni Krsna gege boseje. Lehin na wan ma nitelorun. Ise toye ke se lati fun Krsna ni itelorun. Lehin na gbogbo eyan mani itelorun. Tasmin tuṣṭe jagat tuṣṭa. Ti Krsna bani itelorun, gbogbo eyan lomani itelorun na. teba dami si orisun igi, lesekese ni gbogbo ara igi na ma l'omi. Krsn ani igi nla, ati orisun igi na, egbiyanju ke fun Krsna l'omi. Ekorin Hare Krsna, ke tele awon ofin na, gbogbo nkan a dara fun yin.