YO/Prabhupada 0527 - We are not Loser by Offering Krishna. We Become Gainer Only



Lecture on BG 7.1 -- Los Angeles, December 2, 1968

Prabhupāda: seni ibeere kankan?

Jaya-gopāla: se iwa ife ni taba gba prasadam lowo olulufe wa?

Prabhupada: Beeni. O yeke fun kesi gba. Dadāti pratigṛhṇāti, bhuṅkte bhojayate, guhyam ākhyāti pṛcchati ca. Teba si okan yin si Krsna asi fun yin ni ilana nkan toye ke se. Setiri. Teba sen nkan fun Krsna te sofun pe, Krsna eti se nkan to po fun wa. Oye ki wo jeun kin to jeun. Inu Krsna asi dunsi. Beeni.Otan lehin igbati Krsna ba jeun asi fisile gege boseje. Pūrṇasya pūrṇam ādāya pūrṇam evāvaśiṣyate (Īśo Invocation). Awan fun Krsna ni nkan iyen o wipe Krsna... Krsna le jeun sugbon nitoripe odindin loje, osile fi gbogbo ounje na gege boseje. kole ye awon eyan pe kosejo ipadannu tab fun Krsna ni nkan. ati jeere gan. Ati jeere nikan. teba si woso to da fun Krsna, eyin na leri. ife teni lati ri nkan to da ti yonju niyen. lehin eleyi kosi besele ni ifarafun awon nkan aye yi mo. teba fun Krsna ni nkan to da eyin na ma ni nkan to da. teba se nkan to da fun Krsn eyin na le je ounje na. tin ba kun oju mi kosi bi mo seferi bose rewa to, sugbon tin ba mu digi si iwaju oju mi, mole ri ara mi. gege na irisi kanna leni pelu Krsna. Olorun da eyan gege bi oun seje. teba se nkan to ma je ki inu Krsna inu eyin na ma dun. Krsna osi ni iwulo fun ise teyin se. O pe fun ara re teba gbiyanju lati je ki inu re dun, inu eyin na ma dunsi. egbe imoye Krsna wa leleyi. egbiyanju lati waso to da fu Krsna kefun ni ounje to da, egbiyanju lati fun ni nkan to da ni gbogbo 'gba. bayi eyin na le fibi sanbi ninu gbogbo awon nkan teyin fun.Imoye Krsna leleyi ( Isimi)

gege bi iru aja ni aisan ile-aye yi seri. Seri, bayi ni iru aja seri. kosi besele se ko naa tan, asi pada bi tele. (Erin). Se ri. awon eyan wanyi fe gbadun " Ti Swamiji bale funwa ni gbadun lati awon mantra die," awon eyan ma wa. Seti ri. Nigbati Swamiji basowipe " Iranu nigbogbo eleyi, epaati ke wa si Krsna". Eleyi o da. nitoripe ofe ki iru re wa bayi. ko s'aduru ipara tele fi si, asi wa bosewa (Erin) Aisan to wa niyen. Awon eyan fe nkan aye yi.Otan. " taba le fi mantra fi gbadu ara wa, nkna ti awon eyan fe niyen, oh, odaa gan. Ejeka mu awon oogun toma jeka sironrun, tama bere sini ronu pe ijoba orun lawa" Nkan ton fe niyen. wan fe gbe ninu ijoba orun awon ode. Sugbon tawa ba fun wan ni nkna gidi wansi fisile.

Oda. Ekorin