YO/Prabhupada 0538 - Law Means the Word Given by the State. You Cannot Make Law at Home



Janmastami Lord Sri Krsna's Appearance Day Lecture -- London, August 21, 1973

Lati ko wa ni nkan nidi ti Krsna sen farahan. Yadā yadā hi dharmasya glānir bhavati bhārata (BG 4.7). Krsna sowipe, "Arjuna, ma sokale wa, ti awon iwakuwa ba wole sinu ilana aye mimo". Dharmasya glānir bhavati. kinitumo dharma? isotunmo dharma ni dharmāṁ tu sākṣād bhagavat-praṇītam (SB 6.3.19). dharma niyen. Dharmāṁ tu sākṣād bhagavat-praṇītam. kini isotunmo ofin? Oro ti ijoba baso ni isotunmo Ofin. Eyan o le da awon ofin re ile re. Kole sese. ounkoun ti'job a ba so lema se, " e se bayi," ofin niyen gege na awon ofin Olorun ni isotunmo dharma. dharma niyen. Isotunmo to rorun. moti da dharma temi sile,okurin mi atun da dharma tie sile, dharma koniyen. Nitorina ni Bhagavad-gita se paari sibe, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ (BG 18.66), ati teriba fun Krsna - itumo dharma niyen. dharma imi niyen, dharma koniyen. bibeko, kilode ti Krsan se sowipe sarva-dharmān parityajya: efi gbo eleyi sile? osowipe dharma-saṁsthāpanārthāya sambhavāmi yuge yuge: "lati da awon ofin esin nitarina nimosen farahan". lehin na osowipe, sarva-dharmān parityajya. itumo yen niwipe awon dharma ti awon eyan da, dharma gidi koniyen. nkan ti Olorun fun wa ni itumo dharma. sugbon awa oni oye nipa eni t'olorun je tabi oro to so. awujo awon eyan niyen. sugbon Olorun wa- awon eyan ofe o gba. bawo ni alafia se fe wa? Ofin na si wanbe. Krsna sowipe bhagavān uvāca. Vyasadeva si ko bhagavān uvāca. Eyan gbudo mo nkan ti bhagavan je. Vyasadeva oba ti ko Krsna uvaca. Rara teyan ba si Krsna mo, nitorina lose ko ninu gbogbo ese iwe na, śrī bhagavān uvāca. Bhagavān si wanbe. Bhagavān n'soro. gbogbo awon acarya logba nkan ti Bhagavān baso. Rāmānujācārya, Madhvācārya, Viṣṇu Svāmī. ati Oluwa Caitanya Mahaprabhu pelu Śaṅkarācārya oun gba pe Kṛṣṇa-sa bhagavān svayaṁ kṛṣṇa. oro-ase awon acarya, ni aye atijo awon, Vyāsadeva, Nārada, Asita, gbogbo wa lagba pe Olorun ni Krsna. Arjuna si gbo lati Krsna lehin toni oye Bhagavad-gītā, osowipe, paraṁ brahma paraṁ dhāma pavitraṁ paramaṁ bhavān puruṣam ādyaṁ śāśvatam (BG 10.12)

gbogbo nkan lowanbi ni orile-ede India asi ni, awon dukia lati monipa Olorun. Nkan to rorun. Gbogbo nkan lonti daale. sugbon awa oni gba. kini atunse fun aisan yi? gbogbo wa lan wa alafiaa, sugbon awa oni gba nkan tioni funwa. Aisan wa niyen. Egbe Imoye Krsna wa fe ko awon eyan bonsele ji imoye Krsna ton sun ninu okan wan. bibeko, bawo ni awon omo-ilu America ati Europe tio gbo nipa Krsna ri lodun merin si marun sehin, bawo lojepe wanti mu imoye yi ni pataki? Imoye Krsna wa ninu okan gbogbo eyan. agbudo jisoke. wanti salaaye nipa re ninu Caitanya-caritamrta:

nitya-siddha kṛṣṇa-bhakti 'sādhya' kabhu naya
śravaṇādi-śuddha-citte karaye udaya
(CC Madhya 22.107)

asi jisoke. Ife fun Krsna ati ifarasi Krsna gbogbo e lowanbe, ninu okan gbobo eyan, sugbon oti gbagbe. lati ji imoye Krsna ninu okan awon eyan ni ipinnu egbe wa yi gege bi igbaten sun, mogbudo kigbe oruko yin keto ji "Okurin bayi bayi, edid soke, enise se". kosi iye-ara mi tole sise teban sun, sugbon eti yin ma sise. Nitorina ni aye tawayi awon eyan o fe gbo nkankan mo, taba si korin Hare Krsna maha-mantra yi, onitoun ma jisoke. ale se.