YO/Prabhupada 0542 - What is that Qualification of the Guru? How Everyone can Become Guru?



Janmastami Lord Sri Krsna's Appearance Day Lecture -- London, August 21, 1973

Krsna sowipe ācāryaṁ māṁ vijānīyān: (SB 11.17.27) egba acarya gege bi temi" Kilode? Mo ri edabi okurin. awon omo re sin pe ni baba, tabi ojoo okurin kilode toye ka rowipe asi da bi oloun? nitoripe gege bi Olorun sen soro loun na sen soro. otan. nitorina, kofi nkankan kun. Krsna sowipe sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). Guru asowipe e teriba fun Krsna tabi Olorun. Oro kanna loje. Olorun sowipe man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). Guru sowipe eronu nipa Krsna nigbogbo igba, egbudo gbadura si, kesi di elesin re. Kosejo ayiko Nitorpe ounkoun ti Olorun ba son loun na ma so, nitorina lose je guru. teyin bawo pe osi da bi wipe okurin lasan loje sugbon nitoripe otitoi kanna lon so gege bo sewa ninu awon Veda tabi gege bi Olorun se so, nitorin loseje guru nitoripe koni se awon iyipada iranu nitorina lose je guru. Isotunmo niyen, Osi rorun gan Caitanya Mahāprabhu ti sofun gbogbo wa ka di gurur. gbogbowa. Nitoripe awon eyan niidi fun guru. ile-aye yi kunfun awon asiwere, nitorina lase nidi fun guru to po sugbon kini amuye guru? bawo lose jepe gbogbo eyan lolo di guru? nitoripe Caitanya Mahāprabhu sowipe , āmāra ājñāya guru hañā tāra ei deśa (CC Madhya 7.128). itumo Ei desa niwipe, ibikibi teba wa eledi guru nibe ke fun awon eyan ni imoye kasowipe adugbo tewa kere gan, eledi guru fun adugbo yen kesi gbawan la " bawo lasele se? Mi o ni oye nipa eto iwe, mioni imoye kankan " bawo ni mosefe di guru to ma fun awon eyan nigbala?" Caitanya Mahāprabhu sowipe ko le . Yāre dekha tāre kaha 'kṛṣṇa'-upadeśa (CC Madhya 7.128). amuye teni niyen teba fun awon eyan ni oro yi lati Krsna, eyin na ti di guru. Krsna sowipe, arva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). Ese waasu ke bee awon eyan " Sa edakun e terib afun Krsna". Eledi guru bayi. Ororun go. Krsna sowipe, man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). eyin na le sowipe " E di elesin Krsna, ke dobale. Ile-Olorun leleyi; Krsna leleyi. Edakun e wa. E teriba fun teba tunfe ele fun ni patraṁ puṣpaṁ phalaṁ toyaṁ (BG 9.26). teyin o ba fun ninkankan.. nkan to rorun niyen enikeni lole ri ododo kekere, tabi eso kekere, tabi omi kekere. Ko le rara"

Amuye guru niyen. konsepe Guru fi agabra idan fihan wa nitorina lose di guru Emi na ti seyi fun ara mi. awon eyan yinmi logo pe moti se yanu, iyanu timo se niwipe mo mu oro Caitanya Mahāprabhu: yāre dekha tāre kaha 'kṛṣṇa'-upadeśa (CC Madhya 7.128). asiri towa niyen. eyin na ledi guru. kon sepe eyan pataki nimi, tabi orisa tolagbara towa lati ibi teyin o mo. beeko - Nkan to rorun gan