YO/Prabhupada 0548 - If You Have Come to the Point of Sacrificing Everything for Hari



Lecture -- New York, April 17, 1969

Beena So ārādhito yadi haris tapasā tataḥ kim (Nārada Pañcarātra). Awa n' saadura si govindam ādi-puruṣaṁ, Eda talakoko tonpe ni Hari. Awon iwe mimo Veda sowipe ārādhito yadi hariḥ. Teyin ba ti de ipo toje pe eyin s'aadura si Hari, Eledumare, tapasā tataḥ kim, kosidi fun awe gbigba, ati awon adase yoga, eyi tabi toun, awon ebo to po, gbogbo lo ma tan. Kosi di fun gbogbo awon isoro wanyi teyin ba ti wa sori ipo lati fun Hari ni gbogbo nkan teni. Ārādhito yadi haris tapasā tataḥ kim. And nārādhito yadi haris tapasā tataḥ kim. teyin ba se awon awe gbigba wanyi, awon ebo, awon ise esin, gbogbo nkan wanyi, sugbon mio mo eni ti Hri je: Iranu loje, iranu loje. Nārādhito yadi hariḥ, nārādhitaḥ. Teyin o ba wa sori ipo lati s'aadura si Hari, lehin na gbogbo awon nkan wanyi iranu lonje. Tataḥ kim. Antarbahir yadi haris tapasā tataḥ kim. Teyin ba ri Hari ninu yin ni gbogbo'gba teyin basi ri Hari ni'ta, inu ati'ta... Tad vantike tad dūre tad... kini ese iwe yen na? Īśopaniṣad? Tad antare... Dūre tad antike sarvasya. Hari wa nibikibi, beena enikeni toba ri Hari, antike,nitosi, ati... nibi tojina, ninu, nita, kole ri nkankan afi Hari. Bawo lose se? Premāñjana-cchurita-bhakti-vilocanena (Bs. 5.38). lehin igba teyan ba wole ninu ife Oluwa, kole ri nkankan mo afi hari. Bi iwo re se ma ri niyen. Beena antarbahir yadi hari, inu tabi nita, teyin ba ri Hari, Krsna, tapasā tataḥ kim, lehin na kini iwulo gbogbo awe teyin gba ati awon inira wanyi? Eyin wa lori ipo to gaju. Nkan tafe niyen. Nanta-bahir yadi haris tapasā tataḥ kim. Teyin o ba ri ninu ati nita Hari nigbogbo'gba, kini iwulo gbogbo awe gbigba ati inira yin? Nitorina laaro lawa sen korin mantra yi, govindam ādi-puruṣam tam ahaṁ bhajāmi. Awa o ni'se imi ju bayi lo. Afi lati fun Govinda nitelorun, Eda to gaju, Krsna. Lehin na gbogbo nkan ma wa ni pipe. Pipe loje, adure si na si je pipe, awon olufokansi re na si je pipe. Gbogbo nkan loje pipe.

Ese pupo.