YO/Prabhupada 0552 - How to Stop this Repetition of Birth and Death - I am Drinking Poison



Lecture on BG 2.62-72 -- Los Angeles, December 19, 1968

Prabhupāda: Jāniyā śuniyā biṣa khāinu. Momo nipa eleyi. Moti gba nipa re. Sugbon,... Jāniyā śuniyā biṣa... Gege bi ole. Jāniyā śuniyā, awon oro wabyi o wa pataki fun. Imo nitumo Jāniyā, ati igboran nitumo śuniyā. Beena eni toje ole mowipe " Tinba jaale wonle timisun ewon." O ti gbo na ninu awon iwe mimo pe " Ma jaale. Lehin na wa lo si orun apaadi." Oti gbo lati awon iwe mimo ode ti ri pel'oju re na. Oti jerisi na, sugbon lesekese tonba ti fi sile latinu ewon, atun lose asise tose tele. Jāniyā śuniyā biṣa khāinu. A mo, ati gbo lati awon iwe mimo, lati awon olori, lati iwe Veda, pe " Moti gba ara eda iranu yi, lati jiya lowo awon isoro meta aye; sugbon mio si fe gbiyanju lati fi ipaari si eto satunse ibimo ati iku. Moti mu majele niyen." Jāniyā śuniyā biṣa khāinu. Hari hari biphale janama goṅāinu. Awon orin wanyi ni itosona to po gan. Awa ti mu majele yi pel'oju to la. Tesiwaju.

Tamala Krsna: Enikeni tio ba ni imoye Krsna, botilejepe o lagbara gan lati ni idari lori iye ara re pelu awon ona eke, o daju pe nigba die asi wolule, nitoripe toba laaye di lati gbadun ara re, lesekese loma se." 63: " Lati ibinu, aimokan ma jade, lati aimokan, iranti re ma sonu. Ti iranti o ba daju, ogbon re ma sonu, ti ogbon re ba sonu eyan na ma subu sinu ile aye yi."

Prabhupada: Ipo wa niwipe, ara eda yi lani. Iye ara nitumo Ara ati awon olori ara yi lon pe ni iwako, okan wa ni iwako iye ara wa. Pelu okan wa lawan ronu, ni ifarasi ati ise sise, eto sayensi yi, wa labe ogbon wa. Lori ogbon wa, mosi joko. Emi l'emi. Beena b'awa se bosinu owo maya, ni wonn juwe nibi, pe lati ibinu, aimokan ma bere, alti aimokan yi, iranti wa ma paare. Iranti to sonu. Moti gbagbe pe ara mi ko nimi, Emi ni mo je, aham brahmāsmi; Nkankana nimo je pelu Brahman to gaju, emi, odindin. Pe moti gbagbe. Ti iranti wa bati sonu, lesekese ti moma gbagbe pe emi nimi, masi bere sini rowipe mo paarapo pelu aye yi, itanraeni. Ogbon na ti sonu. Oye kin lo ogbon mi fi wo awon ise okan mi - ironu, ifarasi ati ise sise - ati nitoripe okan mi o ni o le duro sibi kan, iye ara mi na o le wa paapo, nitorina moti wo lule. ìtúpalẹ̀ gbogbo nkan ton sele ninu ara eda leleyi. Tesiwaju.

Tamala Krsna: 64: " Eni tole ni idari lori iye ara re pelu awon ofin tio ni idimu tabi itara si ounkooun le ni ore-ofe Oluwa."

Prabhupada: Beeni. Ati subu. Bawo lase subu? Ati wolule si ipo igbadun iye ara wa. Nitorina egbodo jade kuro ninu awon iye ara, ke si n idari lori iye ara wanyi. Ona imora eni leleyi. Boya eyin fese adase ninu yoga tabi bhkati, ise ifarasi Oluwa, lati ni idari lori iye ara wa ni ibere.