YO/Prabhupada 0561 - Demigods Means Almost God. They Have Got All Godly Qualities



Press Interview -- December 30, 1968, Los Angeles

Akoroyin: Eje ko yemi na. Seyin sowipe awon eyan wa lori osupa?

Prabhupada: Beeni.

Akoroyin: Won wa. orisa de ni won?

Prabhupada: Beeni.

Akoroyin: Orisa niwon. Bawo leyin semo?

Prabhupada: Lati iwe mimo, iwe Veda.

Akoroyin: Iwe mimo wo niyen?

Prabhupada: Iwe mimi Veda.

Akoroyin: Bawo losen ko sile?

Prabhupada: V-e-d-i-c.

Akoroyin: Oh, Vedic. E dakun,

Prabhupada: Beeni.

Akoroyin:E dakun ema binu, tinba bere....

Prabhupada: Kosi wahala...

Akoroyin: Mio fe ke binu.

Prabhupada: Nigbami mio le gbo bee sen soro.

Akoroyin: Mo mobe.

Prabhupada: Iyato laarin orile-ede niyen. Kon se nkan pataki. Beeni.

Akoroyin: Lati awon iwe Veda wanyi won sowipe, awon eyan wa lori osupa.

Prabhupada: Oh beeni.

Akoroyin: Sugbon orisa niwon.

Prabhupada: Itumo orisa niwipe awon eda ton gaju awon eda eyan niwon. Awon eda na lone bi awa na sugbon iwonb aye won, awujo toni, imoye mimo, gbogbo e lo gaju tia lo nitorina lonse pe won ni orisa. Die loku kon d'Oluwa. Bonse ni ilosiwaju to niyen. Itumo orisa niwipe iyato die lowa laarin won at'Oluwa. Won ni awon iwa oluwa, won le ni idari lori awon oun aye yi. Imi ninu won lon toju omi ojo, imi lon toju oru. beyin na se ni awon olori apa bayi, olori apa toun, beena kilode teyin rowipe agbaye yi, kosopolo kankan leyin re atii wipe awon olori orisirisi lowa ati wipe ijoba wa? Awa eyan o fe gba. Iseda. Kinitumo iseda? Awon nkan to dara bayi ton ya wa lenu won sise fun ara won, laisi eni to tonju won? Se ri bayi?

Akoroyin: Mo mowipe ibeere toyeka bi ara wa nigbogbo'gba niyen. O wa pelu awon nkan toye ka sewaadi fun...

Prabhupada: Sugbon pel'ogbon roi lasan oye kan ri wipe won fe jeki sputnik kan fo lori afefe, aimoye awon opolo sayensi ton sise leyin re. ati aimoye awon sputnik wanyi tonpe ni isogbe, ton fo lori afefe, koseni kankan to wa leyin e. Kileleyi? Se opolo to da niyen?

Akoroyin: Mio mo. Oye kin ronu nipa re.

Prabhupada: Oye ko mo. Bawo losefe je. Oyeki opolo kan wa leyin e. Ton sise.

Akoroyin: Nisin seyin sowipe osupa.. Kini mofe so na? ni ile olori egbe fun awon orisa?

Prabhupada: Rara, awon isogbe towa lori ipo kanna po gan. Awon isogbe wanyi po gan. Ikan ninu won l'osupa je.

Akoroyin: Se ikan ninu awon orisa yi ti wa saye yi ri tabi...

Prabhupada: Teletele won man wa nigbati awon eyan le ri won. Se ri bayi?

Akoroyin: Nigbateyin sowipe teletele se iye wipe aimoye odun seyin tabi ....

Prabhupada: Rara. ko ju odun ẹgbẹ́ẹdọ́gbọ̀n seyin.

Akoroyin: ni odun ẹgbẹ́ẹdọ́gbọ̀n seyin, nigbana se awon eda wa laaye yi?

Prabhupada: Beeni, awa si ni ijeerisi, nigbami awon eyan man sebo nla, awon orisa ma wa lati awon isogbe imi, tonba fun won ni iwe apiyesi, Akoroyin; Nibo? Sibo..? Nkan teyin soyi ninu iwe mimo Veda lowa?

Prabhupada: Beeni.

Akoroyin: Mori bee. Mori bee.

Prabhupada: Emi ko nimo daale.

Akoroyin: Oh, Momobe! Rara! Nkan ti mon so ko niyen. Sugbon mofe mo nibo...