YO/Prabhupada 0570 - Even Misunderstanding Between Husband and Wife - No Question of Divorce



Press Interview -- December 30, 1968, Los Angeles

Akoroyin: Se ikorasile wa laarin awon tọkọtaya ni India.

Prabhupada: Beeni. Awon omo-okurin at'obirin nisin ton ti lajo s'odi, awon lon se ikorasile wanyi. teletele, ti'ja bawa laarin awon oko ati iyawo, kosejo pe won fe korasile. Emu ile aye mi fun apeere. Onil nimi teletele. Nisin moti fi sile. Beena oni awon igba ti mio gba awon nkan ti iyawo mi se, sugbon kosejo pe mofe fisile. Se ri bayi? Mio tie laala na, oun na o laala na. Awa o mo iru nkan bayi. Nisin won t mu wa.

Akoroyin: Asa ilu geesi.

Prabhupada: Ah, beeni.

Akoroyin: Seyin ni awon akeeko ni India gan?

Prabhupada: Beeni. Awon temi ko, sugbon awon egbe mi, egbe yi da gan.

Akoroyin: Awon melo.... melo..

Prabhupada: Oh, aimoye. Ninu imoye Vaisnava yi, imoye Krsna, awon olufokansi re po gan. Won fee koja ju daje gbogbo olugbe na.7 Eyin e bere lowo arakurin olugbe India asi soro nipa imoye Krsna fun yin. Ole ma je akeeko temi sugbon oni awon eyan mimo ton sise yi.

Akoroyin: Se eyin gb a ikeeko kankan...

Prabhupada: Beeni, Guru Maharaja mi lose itebomi funmi, iworan re leleyi.

Akoroyin: beena moti ri.

Prabhupada: Beeni. Beena nigbati orile ede yin si fe iwe-eri lati jekin di olugbe- tayeraye, mosi gba iwe-eri lati awon egbe mi pe won funmi ni itebomi. Otan. Sugbon bibeko, ni orile-ede wa, kosidi fun iwe-eri.

Akoroyin: Looro imi, kosi nkankan biwipe eyin losi ile iwe alufaa ni India teyin le lo lati keeko fun bi odun meerin.. Prabhupada; Rara, ile awon alufaa leleyi. Beeni, ile-alufaa yi wa. Asi ni egbe wa, egbe Gaudiya Math. Won ni ju apa-ile ise ogorun, beeni.

Akoroyin: Sein man lo lati keeko lori eto kan soso?

Prabhupada: Beeni, Eto fun ikeeko yi ni awon iwe meji, meta wanyi, otan. Enikeni le ka iwe wanyi. Bhagavad-gītā ati Śrīmad-Bhāgavatam tabi Caitanya-caritāmṛta. Eyin ma ko nipa gbogbo nkan. Awon iwe toye ke ka po gan. Nitoripe Bhagavad-gita si je iwe to da gan, teyin ba ni oye nipa ila kan soso eti ni imoye Na. Seri bayi? Beena, nkan to daju tosi ni'yi. Nitorina lase se itejade Bhagacad-gita yi gege boseje. E je ki awon olugbe yin kon ka iwe na, konse ibeere, kon gbiyanju larti ni oye nipa egbe wa. Akoroyin macmillan ti te ikan jade.

Prabhupada: Beeni, Macmillan lon te iwe wa jade.