YO/Prabhupada 0572 - Why Should You Say? 'Oh, I cannot allow you to speak in my church'



Press Interview -- December 30, 1968, Los Angeles

Akoroyin: seyin mowipe, lati imoye to daju, seyin rowipe egbe yin le ni ilosiwaju ninu orile-ede America?

Prabhupada: Fun igba timoti wa moti riwipe , aye wa fun lati dagba. ( isinmi...)

Akoroyin: Beena oro yin o yato si ti Moses tabi Kristi tabi ounkoun ninu awon olori pataki. Yi awon eyan ba tele awon ofin mewa wanyi, ton tele,

Prabhupada: Awa o sofun awon eyan pe efi esin yin sile. E wa s'odo wa." Sugbon e tele awon ofin tiyin. gege bi awon akeko. Nigbami ni India o lesele pe leyin igba ti awon eyan bati paari idanwo lori M.A ni ile-iwe eko giga, won si ma wa si awon ile-eko giga lati keeko si. Beena kilode tonse wa? lati gba imoye si. Beena eyikeyi ninu awon esin teyin ban tele, sugbon teyin ba ni oye to posi ninu egbe imoye Krsna wa yi, kilode teyin o sele gba s'okan teyin ba mu eto Oluwa ni pataki? Kilode teyin o sele sowipe, " Oh, onigbagbagbo nimi. Jew nimi. Mio le wa si ìpàdé yin." Kilode teyin sowipe " Oh, Mio le jeke soro ninu ile-ajosin mi." Tinba soro nipa Oluwa, kini atako tryin ni?

Akoroyin: Beeni, mio le ba yin jiyan. Mo mope eyin gan mo, osi dami loju pe titi disin, fun apeere, awon ijo katholiki oti le wa sibi lati da ile-ajosin sile. Iyen o si mo.