YO/Prabhupada 0574 - You cannot Kill the Body without Sanction. That is Sinful



Lecture on BG 2.19 -- London, August 25, 1973

" Fun emi wa kosejo nipa ibimo tabi iku. Latigba toti wa laaye kosejo pe konisi mo nijokan. Alainibere loje, tayeraye, kole ku. Koni ku ti ara eeda yi ba ku."

Beena, lona orisirisi, Krsna fe dawa loju pe emi wa tayeraye lo wa fun> Ona orisirisi. Ya enaṁ vetti hantāram (BG 2.19). Ti'ja ba wa, beena toba pa enikan tabi.... Beena Krsna sowipe teyan ba rowipe " Okurin yi lo pa okurin to ku yi," tabi " Okurin yi ls pa ikeji," iru imoye yi o daju. Koseni tole pa enikeni. Lehin na awon oni-peran na ma sowipe " Lehin na kilode teyin sen pariwo pe awan fi ku pa?" Won fiku pa ara eda na, sugbon eyin o le fiku pa enikeni lehin igbati ofin na ti sowipe " ema fiku pa." Itumo re niwipe eyin o le fiku pa ara eda yi lai ni ase lati se. Eyino le fiku pa. Botilejepe emi wa o l ke, ara eda na le ku, beena eyin o le fiku pa ara eda yi lai ni ase lati se. wa elese niyen. Fun apeere, okunrin ton gbe ninu ile kan. Beena ti bakana tabi keji e le kuro niu ile na. Beena okurin na asi losibomi. Oto oro niyen. Sugbon nitoripe eyin ti lekuro ninu ile re, omo-odaran niyin. Eyin o le sowipe, " Botilejepe mo ti le kuro, asi ri ibomi." Rara. Oda, sugbon eyin o lagbara kankan lati le kuro. Aye re to daju lowa ninu ule re, nitoripe eyin ti le kuro, omo-odaran leyin je, oye kan fiya jiyin.

Beena awon oni peran tabi enikeni ton fiku pa eda kankan, kosi bonsele jiyan. pe " Nibi, Bhagavad-gita sowipe emi wa o le ku, na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20), lehin igba ti ara eda yi ma tan. Beena kilode teyin sen pariwo pe ati pa ara eda yi?" Beena koko oro to wa leleyi wipe, eyin o le fiku pa ara eda na. Kose se. Iwa ese niyen. Ubhau tau na vijānīto nāyaṁ hanti na hanyate. Beena koseni toye ko pa elomi, awon eyan o gbodo pa ara won. Ikan soso niyen. l'ona to yato Krsna sowipe na jāyate: awon eda o le nibimo. Ara wa lole ni ibimo tabi iku. Awon eda, ina mimo, lehin na nkankana lonje pelu Krsna, Krsna na o ni ibini, tabi ike.. Ajo 'pi sann avyayātmā. Eyin ma ri ninu apa Kerin. Ajo 'pi. Kṛṣṇa is aja. Eni tio le ni ibimo nitumo Aja. Beena, nkankana laje pelu Krsna, awa na o le ni ibimo kankan. Ibimo ati iku ara eda yi, awa ti wole sinu eto ara yi tojepe ti ara eda yi ba ni ibimo tabi iku awa sima ni inira tab idunnu na. Kosi igbadun kankan looto. Ibimi ati iku, awon nkan pelu inira topo lonje... At salaaye tele. Imoye emi wa si tanka lori gbogbo ara wa. Nitorina, inira ati igbadun wanyi wa lori eto ara eda yi. Beena Krsna ti fun wa ni itosona nipa awon inira ati igbadun wanyi, mātrā-sparśās tu kaunteya (BG 2.14), ton fowokan araq wa nikan, ema jeki awon nkan bayi funyn ni'nira. Tāṁs titikṣasva bhārata. Gege bayi tawa ba ronu nipa ipo aye wa, imora-eniu, base yato s'ara eda yi... Looto, sasaro niyen je. Taba ronu nipa ara wa, nipa ara eda yi, imora-eni niyen je. Emi ko l'ara eda yi nitumo imora-eni, ahaṁ brahmāsmi nimi, emi nimi. Imora eni leleyi.