YO/Prabhupada 0580 - We cannot Fulfill our Desires without Sanction of God



Lecture on BG 2.21-22 -- London, August 26, 1973

Sarvasya cāhaṁ hṛdi sanniviṣṭaḥ, " mowa ninu okan gbogbo eyan." E sewaadi nipa Oluwa, nipa Krsna. Nibikibi, ninu gbogbo iwe mimo Veda, guhayam. Towa ninu okan nitumo Guhāyām . Sarvasya cāhaṁ hṛdi sanniviṣṭo mattaḥ smṛtir jñānam apohanaṁ ca (BG 15.15). Olori too gaju, Krsna, on joko nibe, osin funwa ni itosona, "Nisin awon eda fe gbadun ife okan won bayi." On fun itosona si iseda aye yi. " Nisin e mura lati fun eda asiwere yi ni ara imi. O fe gbadun. O da be, e je ko gbadun." Nkan ton sele niyen. Asiwere ni gbogbo wa, awa tida ono orisirisi lati wa laaye. " Mo rowipe." Beena eyin ronu. Lesekese teyin ban ronu... Sugbon awa o le gbadun ife okan yi lai gba ase Olrun. Kolese se. Sugbon awa sin terimo pe " Mofe gbadun ife okan mi," Krsna ti funwa l'ase " O dabee." Gege bi omode tofe nkan tuntun. baba ma fun, " O dabee, gba." Beena awon ara tan gba, pelu ase Oluwa, sugbon osin funwa pelagidi pe " Kilode ti asiwere yi fe gba nkan yi?" Ipo wa leleyi. Nitorina, lehin gbogbo e Kṛṣṇa sowipe, sarva-dharmān parityajya, (BG 18.66) " E fi iwa asiwere yi sile, " Mofe gba ara eda yi, mofe gba ara toun, mofe gbadun aye bayi" - efi gbogbo iranu yi sile."

Beena nibi ninu iwe miko Veda awa ti riwipe Oluwa ati awon eda, won wa ninu okan wa. Awon eda ton gbadun ife okan tonni, olori sin p'ase fun lati gbadun na, prakrti losin fun ni awon ara eda wanyi. " Ara eda leleyi, ,Sa e wa gba>" Nitorina orisun idimu wa tabi igbala ni ife okan wa. Basen nife okan yi si. Teyin bafe ele nife okan lati jade kuro ninu idimu ibimo, iku, ojo arugbo at'aisan, o ti wa. teba si fe tesiwaju pelu iyipo ninu ara eda yi, vāsāṁsi jīrṇāni... Nitoripe eyin o le gbadun ile aye mimo ninu ara eda yi. Ele gbadun ile aye yi ninu ara aye yi. Teyin bafe gbadun aye mimo, e gbodo ni ara mimo. sugbon awa o ni iroyin kankan nipa aye mimo, igbadun mimo, afe gbadun ile aye yi. Punaḥ punaś carvita-carvaṇānām (SB 7.5.30), a'n je nkan tonti tu danu. Imo ako ati abo kana ni okurin ati obirin n;gbadun ni ile. Won si ma lo si ijo ton tu sihoho. Imo ako ati abo na ni gbogbo e ma paarii si. Sugbon won ronu wipe, " Tinba losi ile-sinema tabi ile ton jo nihoho, nkan to da niyen." Beena won pe ni punaḥ punaś carvita-carvaṇānām (SB 7.5.30), won je nkan ton ti je tele. Imo ako ati abo nile, wansi lo si ile-ijo ton tusihoho. Je nkan ton tu danu. Kosi rasa kankan. Kosi nkankan to dun nibe, nitorina, ibanuje won po si. Nitoripe nkankana loje. gege beyin sen je ireke teyin mu omi ireke, teyin ba tun ireke na je, kileyin fe ri ninu e? Sugbon awon eyan wanyi o logobn kankan, won o mo. Won fe ni igbadun tonti ni tele, ton ti gbadun tele. Punaḥ punaś carvita-carvaṇānām (SB 7.5.30). Adānta-gobhir viśatāṁ tamisraṁ punaḥ punaś carvita-carvaṇānām. Eda eyan... eyin ma ri wipe awon aja wanyi, wansi ni imo ako ati abo, kosi ituju kankan. Beena, opolopo awon eyan ma joko sibe lati wo. Itumo woran niwipe, " Tinba le gbadun loju titt bayi." nigbami won se. Nkan ton sele niyen. Punaḥ punaś carvita-carvaṇānām (SB 7.5.30).