YO/Prabhupada 0584 - We become Cyuta, Fallen Down, but Krishna is Acyuta



Lecture on BG 2.20 -- Hyderabad, November 25, 1972

Emi wa o le ku. Na hanyate hanyamāne śarīre. Emi wa o le nibimo tabi iku. Krsna wa tayeraye, Krsna o ni ibimo tabi iku kankan.... Ajo 'pi sann avyayātmā. Kṛṣṇa ti salaye ninu apa Kerin. Aja. Aja l'oruko imi fun Kṛṣṇa. Tabi viṣṇu-tattva. Aja. aja na lawa je. Eni tio ni ibimo nitumo Aja. Beena Krsna tabi Oluwa ati awon eda aye yi, wan wa tayeraye. Nityo nityānāṁ cetanaś cetanānām (Kaṭha Upaniṣad 2.2.13). Iyato kan sos towa niwpe nitoripe awa je iwonba kekere, Nitorina awa sin bosinu agbara ile aye yi. Iyato to wa niyen. Awa tidi cyuta, ati wolule. Sugbon Acyuta ni Krsna. Kole subu. Iyato to wa niyen. Gege bi sanmo. Sanmo le bo ina orun die. konsepe sanmo na le bo gbogbo ina orun. kolese se kasowipe sanmo ti bo gbogbo ofurufu, fun ogorun milli, ogorun meji mili. Sugbon kini mili ogorun marun je fun orun, ton bo gbogbo agbaye? Beena oju wa ni sanmo yi n'bo, orun ko. Beena, maya le bo oju awon eda. Māyā o le bo oju eda to gaju. Rara. Kolese se. Beena ibimo ati iku yi nitori idabo lati māyā. Agbara to wa laarin. Krsna si lagbara to po. Parāsya śaktir vividhaiva śrūyate (CC Madhya 13.65, alaye). Itosona Veda niyen. Otito pipe yi ni agbara to po. Ounkoun taba ri... Parasya brahmaṇaḥ śaktis tathedam akhilaṁ jagat. Ounkoun t'awa ban ri, agbara Oluwa loje. Gege bi ina orun ati orun seje, ati orisa-orun. Orisa-orun.... Orisa-orun nikan ko, awon eda to po na siwa. Ara won sin dan. Wan ni ara ina. Bi awa se ni ara ile yi... Ile lo poju lori isogbe wa. Beena, lori isogbe orun, ina lo po nibe. Bi ile se je ikan ninu awon oun ile marun, ina si je ikan ninu won. Wanti salaye wipe ina o le jo emi wa.