YO/Prabhupada 0592 - You should Simply Come to Thinking of Krsna, that is Perfection



Lecture on BG 2.20 -- Hyderabad, November 25, 1972

Prabhupāda: Beena adase to wa niyen. Egbodo wa sori ipo ironu nipa Krsna. Ipo pipe niyen. Teyin ba sini nkan to po lokan, lehin na ewu nla wa pe eyin le di ologbo, aja, agbonrin, tabi orisa, ounkoun.

Olugbe India: Maharaja, kilode teyin...?

Prabhupāda: Yaṁ yaṁ vāpi smaran loke tyajaty ante kalevaram (BG 8.6). Lasiko iku yin ounkoun teba ni bi ife okan, ara re lema ni laye to kan. Ofin iseda leleyi. ( Isinmi) ni Russia, ni Moscow, awon omo-okurin to wa nibe, won fe parapo pelu egbe imoye Krsna yi. Awon imi si gba itebomi lowo mi, won sin tesiwaju. Gege bi awon omo-okurin wanyi na sen tesiwaju. Beena.. Beena pelu ijerisi timo ni, ibikibi timo tilo, nkankan ni awon eyan. Pelu awon ona eke wanyi lonti da eto communist yi sile (isinmi) Nkankana ni awon eyan. Lesekese taba soro nipa Krsna, lesekese lo daun si. Ijeerisi temi niyen. Looto, oto oro leleyi. Ninu Caitanya-caritāmṛta, wan sowipe, nitya-siddha kṛṣṇa-prema sādhya kabhu naya, śravaṇādi-śuddha-citte karaye udaya (CC Madhya 22.107). Imoye Krsna yi wa ninu okan gbogbo eyan. Sugbon kosini jiji. Sugbon idoti aye yi ti bo mole. Beena śravaṇādi, śuddha-citte. Beena beyin sen gbo bayi... Gege bi awon omo-okurin America wanyi, nialakoko won wa lati gbo nkan timon so. Lati igboran, imoye Krsna lokan won ti jisoke, wan de ti mu ise fun Krsna yi nipataki (Isinmi) Gbogbo eyan loni imoye Krsna ninu okan won. Ilana wa, egbe sankirtana, yi ni lati ji imoye yi soke.Otan. Gege bi okurin ton sun. Lati le jisoke: Dide! Dide!" Uttiṣṭhata jāgrata prāpya varān nibodhata. ilana wa niyen, konsepe. Awa kon so awon eyan di olufokansin Krsna Imoye Krsna yi wa nibe. ibi gbogbo eda leleyi. Krsna sowipe, mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ (BG 15.7). gege bi baba ati omo-okurin. Kolesi isasoto. Sugbon nigbami omode na le jade kuro nile, lati igba omode re. Ole gbagbe eni ti baba re je Nkan imi niyen. Sugbon ibasepo laarin baba ati omode kole tan.