YO/Prabhupada 0595 - If You want Varieties You have to Take Shelter of a Planet



Lecture on BG 2.23 -- Hyderabad, November 27, 1972

Beena ninu ina Brahman, cin-matra nikan loje, eda nikan, kos'emi orisirisi. Emi nikan loje. Gege bi ofurufu. Nkan aye yi na ni ofurufu yi. Sugbon ninu ofurufu yi, kosi awon nkan orisirisi. teyin bafe nkan orisirisi ninu aye yi gan, egboso ni idaboo ninu isogbe aye kan, boya ke wa si isogbe aye yi tabi ke losi isogbe osupa tabi isogbe oorun. Beena, ina Brahman yi sin dan lat'ara Krsna. Yasya prabhā prabhavato jagad-aṇḍa-koṭi (Bs. 5.40). geg bi ina orun sen dan lati isogbe orun, ninu isogbe orun yi, orisa orun na siwa, beena, ninu odo metalokan, ina Brahman yi wa nibe, ninu ina Brahman yi, awon isogbe mimo yi wa nibe. Vaikunthaloka niwon. Krsnaloka ni Vaikunthaloka to gaju. Beena lat'ara Krsna, ina Brahman yi sin jade. Yasya prabhā prabhavato jagad-aṇḍa-koṭi (Bs. 5.40). Gbogbo nkan lowa ninu ina Brahman yi. Sarvaṁ khalv idaṁ brahma. Ninu Bhagavad-gita wan sowipe, mat-sthāni sarva-bhūtāni nāhaṁ teṣu avasthitaḥ (BG 9.4). Gbogbo nkan lo wa lori ina ara Re, ina Brahman...

Gege bi gbogbo isogbe aye yi sen gbekele ina oorun. Ina orun yi ni ina lati ara orun, aimoye awon isogbe aye yi ton gbekele ina orun yi. Gbogbo nkan lon sele lori ian orun yi. Beena ina Brahman ton jade lati ara Krsna, gbogbo nkan sin gbekele ina Brahman yi. Looto, orisiris agbara lowa laye yi. Gege bi ina orun se yato pelu awo re, ati agbara re. Nkan to da ile aye yi niyen. Gege bi awa se ni ijeerisi t'awa. Nigbati koba s'orun ninu awon ilu geesi, ti yiyin ban ro, gbogbo awon eww igi loma tan, asiko ti awon ewe amn jabo niyen. Awon igi lasan loma seku. beena ti igba ojo ba de, t'orun ran, gbogbo awon ewe na ma jade. beena orun yi lon sise ninu agbaye wa yi, beena ina ton jade ati ara eda Oluwa ni orisun iseda. Yasya prabhā prabhavato jagad-aṇḍa-koṭi (Bs. 5.40). Lori ina Brahman yi, aimoye awon Brahmandas ton jade.