YO/Prabhupada 0609 - You are so many Chanting Hare Krsna. That is my Success



Arrival Lecture -- Los Angeles, May 18, 1972

Beena eyin om-okurin at'obirin dada, lodun mefa seyin mo wa si orile-ede yin, emi nikan, pelu sekere lowo. Nisin e po ten korin Hare Krsna yi. Aseyori mi niyen. Ase Oluwa Caitanya Mahaprabhu niyen:

pṛthivīte āche yata nagarādi grāma
sarvatra pracāra hoibe mora nāma
(CB Antya-khaṇḍa 4.126)

Oluwa Caitanya si fe ki " Gbogbo ilu, ninu gbogbo abule lorii agbaye yi, oruko mi ma debe." Krsna loje fun ara re, svayaṁ kṛṣṇa, kṛṣṇa caitanya-nāmine, ton korin oruko re Kṛṣṇa Caitanya. Beena asotele to fisile kolese koma jeere. Oto oro niyen. Beena mosi rowipe " Mofe losi America. Ilu toni ilosiwaju ju ninu aye yi ni America. Tinba le fi danwon loju, won ma gba sokan." Arugbo nimi. Mowa sibi nigbati moni odun adorin, nisin moti pe merindilogorin. Beena moti ni ikolofun. Ni odun 1971, mosi ni gbigbotiki okan. Eyin mo, gbogbo e. Beena ise apinfunni ti Caitanya Mahaprabhu leleyi nisin ninu owo yin. Omo-okurin at'obirin America leyin je, esi logbon, Krsna dee ti funyin ni ore-ofe re. Eyin o kinse talaka. Eyin ni ohun elo to po,ipo gidi. Gbogbo nkan dara aye yi leni. Teyin ba mu egbe imoye Krsna yi ni pataki, orile-ede yin ma ni gbala, gbogbo agbaye ma ni igbala.