YO/Prabhupada 0611 - If you Lose the Spirit of Service, this Temple will become a Big Go-down



Lecture on SB 1.7.27 -- Vrndavana, September 24, 1976

beena olugbe India niwa, ikeeko tani niyen. Ikeeko nikan ko, olufokansi niwa latigba ton bi wa. Enikeni tonba bi si India, nkan pataki loje. Ni aye to keyin won ti gbawe pelu inira to po gan. Awon orisa gan, won si fe kon bi won si India lati ri aye yi gba. Agbaye tawa yi nitumo India, Bharatavarsa. Aye dada wa. Beena ema rowipe - T'aba rowipe " Okuta leleyi," beena kole wa fun igba to pe. Galagraha. vigraha ko loje, sugbon galagraha. Kasowipe moti da ile ajosin yi. Pelu itosona ti moti funwon awon oluko mi si sadura si awon vigraha. Irisi Olorun nitumo Vigraha, rupa. sugbon ti awon eyan yi o ba tele awon ofin wanyi, lehi igbati mo ba ku, o ma di galagraha, isoro, pe " Asiwere Guru Maharaja wa to da ile-ajosin yi sile, loye ka s'adura wanyi, ka jisoke laaro kutu, gbogbo inira wanyi." Nkan ton pe ni galagraha niyen, " O fi inira yi sile funwa." Ewu to wa niyen. Beena ile ajosin nlan yi ma daru, eyin na ma ri wipe gbogbo nkan ti wolule." aawon nkan wanyi doti, koseni ton foju si. Nkan ton pe ni galagrha niyen. Asiwere yi ti funwa ni isoro." Beena nkan tole gan leleyi. T'awa o ba ni'wa pe " Krsna leleyi. Aye lati sise fun leleyi..." Sākṣād-dharitvena samasta-śāstraiḥ... Śrī-vigrahārādhana-nitya-nānā-śṛṅgāra-tan-mandira-mārjanādau. Lesekese Nitorina o ye ka sewaadi, kilode teyin sen se nkan bayi? Kilode teyin sen se nkan bayi...? Lese kese ti iwa fun ise ifarasi Oluwa ba sonu, ile-ajosin yi ma di inira. Boseje niyen. Asi di ile-ajosin nla lati toju. Oma di inira nla. Beena inira loje funwan. Nitorina kole fun wan ni'damu ti nkan ba wo nibi kan. " O dabee, owo taba ni, e jeka koko jeun." Ipo to w aniyen. Vigraha ati galagraha. O ye ko ye yin. T'aba gbagbe pe Krsna wa nibi fun ara re. Oye ka gba lalejo dada. Ka fun l'onje to da,aso to da... lehin na ise lo je. lesekese ti ironu pe " Okuta leleyi" - nigbami won ma sowipe " adura sigidi leleyi"- " awa de ti gba itosona lati fun laso, ... gbogbo inira wanyi." Lehin na otan niyen. Otan. Nkan toti sele niyen nibikibi. Moti ri ni Nasik ninu gbogbo awon ile adura nla nla, kosi pujari kankan, awon aja na sin wa yagbe sibe. won de ti wo gbogbo nkan Beena ni awon orile geesi wanti ti awon ile-ajosin. Awon ile-ajosin nla nla ni London, sugbon won paa won de. Ton ba ni ipade ni ojo Aiku, onile pelu okunrin meji si meta pelu obirin arugbo kan ma wa sibe. Koseni ton wa Nisin awa tin ra gbogbo won. Ati ra aimoye awon ile- ajosin. Nitoripe nisin ko wulo. Ko wulo. Ni Los Angeles, ati ra kan, ati awon to po gan. Ni Toronto, ati ra awon ile-ajosin nlanla wanyi, won ofe ta fun wa mo. Ikan ninu awon alufaa sowipe " ma daana sun ile-ajosin yi, kaada kin ta fun Bhaktivendata Swami. " ( Erin) Bi Ile-ajosin Toronto seri niyen na. ni Melbourne, won sowipe a gbodo tun ile-ajosin na ko Nigbata bere pe "kilode?" O sowipe, " teyin ba lo fun ile adura awa o le ta funyin." Won ko. Seyin mo be? Beena awon eyan wanyi ko dun mo inu won pe " Egbe imoye Krsna yi fe ra ile-ajosin wa lati fi irisi Radha-Krsna sinu e." Ko tewon lorun. Sugbon nkan ton sele niyen. Beena awon ile-ajosin nikan ko ni awon ilu geesi, nibi na. Lesekese teyin ba fi emi ise s'Oluwa sile, ile-ajosin ma di ibi teyin toju nkan si, otan. Ko kinse ile-ajosin mo. Beena agbodo toju emi ise yi dada. Nitorina lawa sen tenu mo - " Kilode ti awon ododo to da o se wa?" Teyin ba rowipe, " Sigidi okuta leleyi. Kini tumo awon ododo tuntun tabi toti gbo? Oye ka fun wan ni ododo otan." Sugbon ko ye yin pe "Krsna leleyi. Agbodo fun ni awon ododo to da." Gege bi emi nisin, teyin ba fun mi ni ododo to lewa, ati teyin ba funmi ni'doti, ewo ninu won loma temi lorun? Seyin ro bee? Beena ti iru ironu bayi o ba sin bee lati bere. pe " awa ma fun sigidi yi ni awon ododo iranu. Kole soro. " Beeni, Koni soro. Sugbon ile aye yin ti tan niyen. Bi atako re se ma bere niyen. Lesekese teyin o ba ni iwa yi mo, bhāva, budhā bhāva-samanvitāḥ (BG 10.8)... Talo le s'adura si Krsna? Ti bhāva, sthāyi-bhāva ba wa. Wanti salaaye ninu Bhakti-rasāmṛta-sindhu, nkan ti bhāva je. sugbon teyin o ba ni bhāva kankan, lehin na eyin wa lori ipo aye yi, kaniṣṭha-adhikārī. Teyin kon saako. Akoo na o le lo titi, Ni jo kan o ma tan.