YO/Prabhupada 0612 - Anyone who is Chanting Hare Krishna, Jihvāgre, with the Tongue, He is Glorious



Lecture on SB 3.28.19 -- Nairobi, October 29, 1975

Awon Gosvami mefa, nigbogbo'gba lon sise, kṛṣṇotkīrtana, ton korin pel'ohun soke. Ona kanna la wan tele: tan korin pel'ohun soke; kesi sise ninu arcana. Nigbogbogba lawa le gbaye lati ni imoye Krsna. Awon ohun ise na ti wa nibe. Caitanya Mahāprabhu has taught us kīrtanīyaḥ sadā hariḥ (CC Adi 17.31). lehin na preksaniya, " oye ka ri." Oti bawa lara mo lati ri awon nkan to po. Idimu tani leleyi. Akṣnoḥ phalaṁ. Teyin ba foju ri awon irisi, awon Vaisnava... Awon Vaisnava, pelu tilaka, pelu kunit, pelu ileke adura, lesekese teyin bari... lesekese t'awon eyan bari awon eyan lati egbe Hare Krsna won man korin, " Hare Krsna," ati fun awon eyan imi laye lati korin na. Aso yi si se pataki. Nigbogbo'gba loyeke wa ninu tilaka, kunti ati sikha, sutra. Lehin na lesekese ti okurin lasan ba ri, " Oh, okurin Hare Krsna leleyi. Oma korin Hare Krsna. Lesekese letii fun laaye lati korin Hare Krsna. Nkan toye ka se niyen. Awon oniranu asiwere wanyi won sowipe " Kinidi fun gbogbo nkan bayi?" Rara. O se pataki. Egbodo wo aso Vaisnava nigbogbo'gba. Nkan to se pataki niyen. Beena prekṣaṇīya: " osi lewa gan lati ri." Bibeko kilode tosen jo won loju? Lesekese loma yasi mimo wansi ma korin Hare Krsna. Orin kiko Hare Krsna yi ko rorun. Awon eyan to po gan man wa sibi sugbon ton ban korin, awon eyan yi o le korin nitoripe ko rorun. Yaj-jihvāgre nāma tubhyam. Ninu śāstra wan salaaye wipe, aho bata śva-pacato 'pi garīyān yaj-jihvāgre nāma tubhyam. Enikeni ton korin Hare Krsna, jihvāgre, pel'ahon, tonba tie bi sinu ebi awon eyan ton je aja eyan na se pataki. Eyan toye kon yin logo loje. Yaj-jihvāgre nāma tubhyam Beena awa ti fun won laaye yi. Lesekese toba korin Hare Krsna, lesekese loma se pataki. Lesekese loma se pataki. Aho bata śva-pacato 'pi garīyān yaj-jihvāgre nā..., tepus tapas te (SB 3.33.7). Itumo re niwipe laaye re to keyin oti s'ebo to po. Nitorina lose ni amuye yi lati korin Hare Krsna. Tepus tapas te jihuvuḥ sasnur āryā (SB 3.33.7). Āryā, Āryan ni awon eyan bayi, awon ton korin Hare Krsna.

Beena oye ka keeko lati korin Hare Krsna nigbogbo'gba. Kīrtanīyaḥ sadā hariḥ, Caitanya Mahāprabhu ti p'ase.

tṛṇād api sunīcena
taror api sahiṣṇunā
amāninā mānadena
kīrtanīyaḥ sadā hariḥ
(CC Adi 17.31)

Hari-nāma,orin kiko Hare Krsna mantra yi, oye ka se nigbogbo'gba. Hare Kṛṣṇa, Hare Kṛṣṇa, Kṛṣṇa Kṛṣṇa, Hare Hare/ Hare Rāma, Hare Rāma, Rāma Rāma, Hare Hare. Beena prekṣaṇīya ihitaṁ dhyāyet. Sasaro leleyi. Dhyāyet śuddha-bhāvena, śuddha-bhāvena. kon se nkan eke. Sugbon teyin ba tie se bi eke, ema si yasi miko pelu orin kiko yi. Iyehn na wa ninu sastra. Beena oruko Oluwa si lagbara toje pe.. nitoripe o wa paapo pelu Oluwa. Dhyāyet. Sugbon lesekese teyin ban korin, ema sasaro, śuddha-bhāvena cetasā, pelu imoye yin, pel'okan yin, pel'ogbon yin. Beena ase to wa niyen.