YO/Prabhupada 0616 - Brāhmaṇa, Kṣatriya, Vaiśya, Sūdra — That is the Natural Division



Lecture at World Health Organization -- Geneva, June 6, 1974

awujo eda tonba tele iwa awon acarya pataki, awon eyan mimo pataki, lehin na koni si isoro kankan. nkan to sele niyen. Ninu Bhagavad-gita, nigbati Krsna Krsna ati Arjuna won soro, beena Arjuna si salaaye nipa awon ibajade ogun, pe awon obirin ma di obirin opo, asi le fun won lati huwa dada, lehin na adharma, awon ofin alainigbagbo ma bere. Beena o sowipe... O sin jiyan pe,

adharmābhibhavāt kṛṣṇa
praduṣyanti kula-striyaḥ
strīṣu duṣṭāsu vārṣṇeya
jāyate varṇa-saṅkaraḥ
(BG 1.40)

varṇāśrama-dharma ni awujo Veda je. T'awa o ba toju varṇāśrama-dharma yi dada, gbogbo awon olugbe ma di varna-sankara, awon olugbe tonti parapo. Brāhmaṇa, kṣatriya, vaiśya, śūdra - isasoto to daju leleyi. Agbodo pin awujo yi... Cātur-varṇyaṁ mayā sṛṣṭaṁ guṇa-karma-vibhāgaśaḥ (BG 4.13). (segbe:) Ko wulo kankan. Awon isasoto wanyi... gege bi awa se ni isasoto adayeba ninu ara wa: ori, apa, ikun, ati ese, beena, awon isasoto wanyi wa nibe. Imi ninu wan je awon okurion ton logbon, awon imi ni iwa jagun jagun, awon imi si feran eto oro aje ati ile ero, awon si fe fi nkan sinu ikun wonlati jeki ikun won kun. Beena isasoto adayeba to wa niyen. Nitorina Krsna sowipe, cātur-varṇyaṁ mayā sṛṣṭam. Ti cātur-varṇyaṁ, Awon okurin ton logbon ju, e ko wan lati di brahmana. Śamo damo titikṣa ārjava jñānaṁ vijñānam āstikyaṁ brahma-karma svabhāva-jam (BG 18.42). Isasoto yi gbodo wa nibe. Awon okurin ton logbon ju, won gbodo lo asiko won lati ko nipa Veda, kon si logon kon pin fun gbogbo agbaye, beena won le mo bonsele fun awon eyan ni itosona fun alafia ninu awujo eda eyan. Itosona to wa niyen. Awon ksatriya, awon lon toju awujo, awon jagun jagun tabi awon ton ni iwa jagunjagun. Ti alebu kankan ba wa, awon lon fun wa ni idaabo. Beena awon ton seto lati gbin awon irugbin ounje, ati awon ton toju awon maalu. Kṛṣi-go-rakṣya vāṇijyaṁ vaiśya-karma svabhāva-jam (BG 18.44). ati awon eyan iyoku ti o le sise bi awon alakowe, tabi jagun jagun tio le gbin ounje, won le fun awon apa meta okurin toku ni iranlowo. awon lon pe ni sudra. Isasoto awujo eda leleyi. Beena nkan ton pe ni varṇāśrama-dharma niyen. Wan ti lo oro dharma. Ise onikaliku nitumo Dharma. Itiraka awon elesin ko nitumo dharma. Rara. isasoto adayeba ati ise onikaluku.