YO/Prabhupada 0617 - There is no New Formula, It is the Same Vyāsa-pūjā, the Same Philosophy



His Divine Grace Srila Bhaktisiddhanta Sarasvati Gosvami Prabhupada's Disappearance Day, Lecture -- Hyderabad, December 10, 1976

Prabhupada: Beena odun ogoji seyin. Mosi ranti nkankana ni odun 1922, nkankana lo sin sele nisin. Kosi nkan tuntun. Agbodo se nkan tuntun. E jeka fi hon boseje; O ma ni aseyori. Seyin ri. Emi towa leyin awon nkan ti mo ko, nkankan loje. "Wanti tan wa je, gbogbo wa la ti sonu." Awujo ton pa emi awon eda yi lon tonwa je. Oye ka mo, awujo to le f'ona tio da han wa leleyi. Ipinnu aye wa ni lati ni oye nipa idanimo mimo tawa ni kasi sewaadi lori ibasepo tai pelu Oluwa, Krsna. Ise gidi tani leleyi. Sugbon awujo ile aye yi nisin tin tonwa je lorisisi ona. Beena mosi ko wipe " Won ti tan wa je, gbogbo wa de ti sonu. E gbawa la, Oluwa, adura wa leleyi. Awa osi mo ona wo toye ka koju si, kasi teriba si ese yin, Eledumare." Beena apa yi si da gan. Beena agodo wa basele tana yi Igbadun ni ina yi je. Igbadun iye ara wa nitumo ile aye yi, asi gbodo yi ina yi pada - si igbadun fun Krsna. Igbadun iye ara wa si wa nibe, sugbon awujo ile aye yi, awujo toti sonu yi, won ti mu igbadun yi fun igbadun iye ara won. Nigbat'aba yi igbadun ara wa yi si Krsna, lehin na ile aye wa ma ni ilosieaju. Bi awon gopi. Looto o dabi wipe awon gopi si ni ifarasi omo-okurin Krsna, fun igbadun iye ara won lonse d'ore pelu Krsna. Rara. Otooro koniyen je. Otooro to wa niwipe awon gopi man mura dada, nitoripe ti Krsna ba ti ri won, Krsna ma ni itelorun, konse fun igbadun iye ara won. Looto awon omo obirin ma mura lati le yi okan omo-okurin si won Beena nkankana lo wa nibi, sugbon igbadun iye ara Krsna lowa fun, fun awon gopi ko." Awon gopi o si fe nkankana. afi ki Krsna ni itelorun. Iyato laarin ife ati ifekufe niyen. Ife wa nibe, osi sese taba yi pada si Krsna. Ife gidi niyen. leyin eleyi ifekufe nigbogbo nkan je. Agbodo ranti. Awon iye ara wanyi o le paari, sugbon teyin ba yi igbadun yi si Krsna, bhakti tabi ife niyen. Teyin ban lo igbadun yi fun ara yin, ifekufe niyen. Iyato laarin ifekufe ati ife niyen. Beena Śrīla Bhaktisiddhānta Sarasvatī Ṭhākura si mo nipa eto yi, base le yi awon ise wa fun itelorun Krsna. Egbe imoye Krsna niyen. "Awa o mo ona wo toye ka koju wa si, teriba si ese yin, Eledumare." "Ati gbagbe Krsna, awa eda ta wa ninu aye yi." Kilode tase wa ninu aye yi? Nitoripe ati gbagbe. Ibasepo wa p[eluu Krsna wa tayeraye. Tio ba kin se nkan tayeraye, bawo ni eyin olugbe geesi se di olufokansi Krsna? Kosi beyin sele di olufokansi Krsna laisi ibasepo kankan. Nitya-siddha kṛṣṇa-bhakti. pelu ilana yi o ti ji soke. Śravaṇādi-śuddha-citte karaye udaya (CC Madhya 22.107). oti ji soke. Ife laarin okurin ati obirin, ko kin se nkan eke. O wa nibe. sugbon pelu awon nkan ton sele, ife yi ma jisoke. Beena, ife wa fun Kresna, ibasepo wa pelu Krsna, tayeraye lowa fun. Jīvera svarūpa haya nitya kṛṣṇa-dāsa (CC Madhya 20.108-109). Sugbon agbodo se awon nkan toma jeki ife yi ji soke. Nkan ta fe niyen. Beena " Atri gbagbe Krsna, awon eda aye yi, ati son gbese itanraeni ta ni." Nitoripe ati gbagbe Krsna, nitorina lasen son gbogbo gbese wanyi. Iru gbese wo? Gbese nivartante mṛtyu-saṁsāra-vartmani (BG 9.3). Lati ni imoye nipa Krsa ni ile aye yi wa fun, sugbon dipo tawa ma ni oye nipa Krsna awa sin gbiyanju lati ni oye nipa sayensi ile aye yi fun igbadun iye ara wa. Ipo wa niyern. Agbara toye ka lo ninu ise wa lati ni oye nipa Krsna, ati lo lati da awon nkan fun igbadun iye ara wa. Nkan ton sele niyen. maya, itanraeni niyen. Nitorina "lasen son gbese itanraeni wanyi." Igbese. Nkan tan son nitoripe ati gbagbe Krsna. Nitorina nisin ati da awon ohun ogun - Russia, America - eyin gbodo sonwo gan. Wanti sonwo gan, Gbogbo imura yi ti bere. wanti loju idaji owo ijoba fun awon ohun ogun wanyi. Dipo kon lo fun nkan imi, won lo fuin agbara ogun, gbogbo ipinle. Beena igbese nla tan so niyen, ti ogun ba de koni si opin kankan, elo lafe san fun ibaje yi. Kilode? Nitorip ati gbagbe Krsna. Otooro niyen. Beena awon eyan wanyi, wanti da akojopo awon orile-ede, won jagun bi aja. Beena awon nkan wanyi o le yanju isoro wa. teyin ba p'ase fun gbogbo agbaye Krsna sowipe, sarva-loka maheśvaram (BG 5.29). Kṛṣṇa loni gbogbo awon nkan wanyi, kilode ti won o fe gba? Oun ni onihin gbogbo nkan. talo da agbaye yi sile? S'awa la dasile tabi baba wa? Rara. Krsna lo da sile. Sugbon gbogbo wa lan ja latii gba, " Ile America leleyi, ile India leleyi, Ile Pakistan leleyi." Ko wulo. Kini iwulo gbogbo eleyi? Ale sowipe awa lani fun odun aadota tabi ogorun lehin na won ma ti wa jade. " E jade" Nibo l'oro yin wa? Sugbon imoye wa o le ye won. Won ja, " emi ni moni eleyi, ile mi leleyi." Won o mo wipe Kṛṣṇa sowipe, tathā dehāntara prāptiḥ (BG 2.13). " Eyin je olugbe America leni. L'ola eyin o tie mo boya ema wa si America, bi maalu tabi eranko America, koseni toma dayin mo. Koseni toba wo eto oselu teyin ni. " Sugbon ko ye won. Sayensi o ye won. Won wa labe itanraeni. Won rowipe " Mo ma wa ninu orile America yi lo titi, eje kin lo asiko mi nilokulo fun America. Kole si ife okan gidi nibe. Prakṛteḥ kriyamāṇāni guṇaiḥ karmāṇi sarvaśaḥ (BG 3.27). Iseda lon se gbogbo awon nkan wanyi, awa kon ronu lasan pe, ahaṅkāra-vimūḍhātmā kartāham iti manyate. itanraeni yi lon sele. Wanti gbagbe Krsna, ati wole sinu ile aye yi, atin son igbese ile aye." Atin son wo. Okunkun nibikibi. Ireti lasan tani niyen, Eledumare." Ifiranse to wa niyen. Awa ninu okunkun.

Beena asi le soro lori eto yi. Kini ago n'so nisin?

Olufokansi: Ago meesan die loku.

Prabhupada: Hmm?

Prabhupada: Beeni. Beena a ma tun soro. Beena nkankana loje, Krsna lon je ko sise, lati ilana parampara lati gba imoye yi. Evaṁ paramparā prāptam imaṁ rājarṣayo viduḥ (BG 4.2). Beena etoju ilana paramparā yi. Ilana parampara ni Vyāsa-pūjā yi je. Lati gba ilana parampara yi nitumo Vyāsa-pūjā. Vyāsa. Alabasepo Vyasadeva ni Guru je nitoripe koni yi nkankan. Nkan ti Vyasadeva ba so, nkankana ni guru yin ma so. Konse pe " aimoye odun toti koja; nitorina moti ni ona imi. " Rara. Kosi ona tuntun imi. Vyāsa-pūjā kanna, imoye kana. Agbodo gba bee, lehin na ile aye wa ma ni ilosiwaju. Ese pupo.

Ajo: Jaya! (end)