YO/Prabhupada 0619 - The Aim is how to Improve Spiritual Life, That is Grihastha-āśrama



Lecture on SB 1.7.24 -- Vrndavana, September 21, 1976

Matir na kṛṣṇe parataḥ svato vā mitho 'bhipadyeta gṛha-vratānām (SB 7.5.30). Gṛha-vratānāṁ matir na kṛṣṇe. Awon eyan tonti bura pe, " Mofe duro sinu ile aye ebi yi, kin bale jeki ipo aye mi dara si, " gṛha-vratānām... Gṛha-vrata. Gṛhastha ati gṛha-vrata won yato si aara won. Itumo Gṛhastha ni gṛhastha-āśrama. Okurin ton gbe pelu iyawo at'omo sugbon tofe ni ilosiwaju ninu eto aye mimo. gṛhastha-āśrama niyen. Sugbon tio ba ni iru afojusun bayi to kan fe gbadun iye ara re, sugbon ton toju ile re, ton toju iyawo, omo - nitoripe ofe gbadun won nkan tonpe ni gṛha-vrata tabi gṛhamedhī. Ni ede Sanskrit oro orisirisi wa fun itunmo orisirisi. Beena awon tonpe ni gṛha-vrata, kosi bonsele ni imoye Krsna. Matir na kṛṣṇe parataḥ svato vā. Pelu itosona ti guru nitumo tabi awon olori nitumo Parataḥ. parataḥ Ati svato vā. Lesekese nitumo Svataḥ. Lesekese kolese se pelu awon itosona wanyi. Nitoripe ibura re niwipe " Mofe wa bayi." Gṛha-vratānām. Matir na kṛṣṇe parataḥ svato vā mitho 'bhipadyeta. Mithaḥ, kolese se lati awon apejo, lati awon ipade, pelu awon ofin, " T'aba fe ni imoye Krsna," Kolese se. Nkan t'enikeni niyen. Agbodo teriba si Krsna fun ara wa. gege basen lo sori ofurufu ninu oko afefe, nkan t'olukaluku niyen. Ti ako afefe kan ba wa ninu alebu kan, oko afefe imi o le ranlowo. Kolese se. Beena, nkan toni'kaluku loje. parataḥ svato vā niyen je. Eyan gbodo mu eto na ni pataki, pe " Krsna fe kinse, beena mofe teriba. Kṛṣṇa sowipe, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66), beena mofe se." Konsepe " Nigbati baba mi base, lehin na emi na ma se," tabi " Ti Oko mii ba se, lehin na emi na mase," tabi "Iyawo mi mase." Rara. Eto t'onikalukku niyen. Eto onikaluku niyen. Kosi idimu kankan. Kosi idimu kankan. Ahaituky apratihatā. Teyin ba fe teriba fun Krsna, koseni tole daa yin duro. Ahaituky apratihatā yayā ātmā suprasīdati (SB 1.2.6). Teyin base fun ara yin ..... O da teyin base paapo, sugbon eyan gbodo se fun ara re na.