YO/Prabhupada 0620 - According to your Guna and Karma you are Engaged in a Particular Occupational Duty



Lecture on SB 1.7.36-37 -- Vrndavana, September 29, 1976

Afi Krsna nikan lole fun yin ni idaabo - koseni kankan. Teyin ba mo nipa eto yi, leyi na eyin o kin se pramatta. Teyin o be de mo, asiwere niyin, pramatta. Afi Kṛṣṇa nikan. Nitorina Kṛṣṇa sowipe, oti funwa ni idaniloju pe, sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). Suhṛdaṁ sarva-bhūtānām (BG 5.29): " Emi l'ore gbogbo eyan. Mole funyin ni'daabo. " Ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo mokṣayiṣyāmi. Beena egbodo gba idaabo lati Krsna; bibeko pramatta, asiwere, mūḍha leyin je. Krsna ti funwa ni itosona pe " E se bayi." Sugbon asiwere niwa, pramatta. Awa sin rowipe " Omo okurin mi ma funmi ni idaabo ti mofe, ore mi ma funmi ni idaabo, ijoba ma funmi ni idaabo." Gbogbo iranu wanyi, pramatta. Itumo pramatta niyen. E gbiyanji lati ni oye re. Pramattaḥ tasya nidhanaṁ paśyann api (SB 2.1.4).

pramatta imi, niwipe awon ton sa tele igbadun iye ara wanyi. Nūnaṁ pramattaḥ kurute vikarma (SB 5.5.4). Ese iwe imi tunwa, nūnaṁ pramattaḥ awon tonje pramatta, awon eyan tio ni ojuse kankan se laye, nigbami ton jale tabi ton se awon nkan tio da - vikarma. Kilode? Nisin pramatta, oun na ti ya were. Nūnaṁ pramattaḥ kurute vikarma (SB 5.5.4). Kilode to sen huwa tole je kan fiyaje? kasowipe okurin kan wa ton jale. Wan ma fiya je. Boya lati ofin ipinle tabi ofin iseda, tabi Oluwa, oma jiya. O le sa kuro lati awon ofin ijoba, sugbon kole sa fi awon ofin Ijoba. Prakṛteḥ kriyamāṇāni guṇaiḥ karmāṇi (BG 3.27). Kolese se. gege bi ofin iseda: teyin ba ni aisan l'ara, eyin ma jiya. Eyin ma jiya lati aisan na. Ijiya to wa niyen. Kosi besele sa kuro. Beena ounkoun teyin ba se, kāraṇaṁ guṇa-saṅgo 'sya (BG 13.22). Teyin ban gbe bi ologbo at'aja, akoran niyen je, guna, ipo aimokan. lehin na ninu aye to kan eyin ma ni ara aja. Egbodo jiya. Ofin iseda aye yi niyen. Beena eni tio ba mo nipa awon ofin wanyi, oma se gan, vikarma. Karma, vikarma, akarma. Oun ton ti juwe nitumo Karma. Guṇa-karma. Guṇa-karma-vibhāgaśaḥ (BG 4.13). itumo Karma ni wipe, gege bonse so ninu sastra, beyin se ni iwa si beena ni karam yin se ma ri: brāhmaṇa-karma, kṣatriya-karma, vaiśya-karma. Ise oluko mimo ati sastra niyen lati se isasoto na, nigbato ba je brahmacari o ye ko sise bayi. " Sise bi brahmana," " Sise bi ksatriya, " Sise bi vaisya ati awon iyoku, "Sudra." Oluko mimo lon se awon isasoto wanyi. Bawo? Yasya yal lakṣaṇaṁ proktaṁ varṇābhivyañjakam (SB 7.11.35). Oluko mimo ma sowipe " E sise bayi." Beena nkan toye ke se niyen. karma niyen, guna-karma. Oluko mimo re ti riwipe onitoun yi ni awon iwa wanyi. Nkan adayeba niyen. Gege bi ile-eko, ile iwe eko giga, awon elomi ma ko lati di oni sayensi, imi fe d'ele ro, tabi oniwosan, tabi adajo. Gege bi iwa akeeko na seri wansi ma salaaye fun, " Se bayi." Beena, awon isasoto merin wanyi, wan daju gan. Pelu itosona guru, nigbato ba wa ni gurukula, o ma gba ise kan, toba si sise na dada... Sva-karmaṇā tam abhyarcya (BG 18.46). Idi gidi fun imoye Krsna niyen. bi guna ati karma re base ri, asi wa iru ise na lati se.

Kosi nkan to buru, teyin ba lo fun itelorun Krsna. Ataḥ pumbhir dvija-śreṣṭhā varṇāśrama-vibhāgaśaḥ (SB 1.2.13). varṇāśrama-vibhāga yi gbodo wa nibe. kini afojusun ti varṇāśrama? Se onitoun na ma ni aseyori toba di brahmana?: Rara. Koseni tole ni aseyori afi toba fun Krsna ni itelorun. Aseyori gidi to wa niyen.