YO/Prabhupada 0630 - There is no Cause for Lamentation, because Soul will Remain



Lecture on BG 2.28 -- London, August 30, 1973

Olufokansi: Isotunmo: " Ni alakoko gbogbo awon eda tio ti wa saaye wa ninu ipo toje pe won o le farahan, wansi farahan tonba ti wa saye, wa tun paare ton ba ti fiku pa gbogbo won. Beena kinidi fun gbogbo ekun wanyi?

Prabhupada: Beena tayeraye l'emi yi wa fun. Beena kosidi fun ekun sisun yi, nitoripe emi wa o le paari. Tobatijepe ara eda yi paari, kosidi fun ekun sisun. awon eyan tio ba ni gbagbagbo pe " Emi wa ninu ara eda yi, pe nibere kosi nkankan..." Beena nibere kosi nkankan, nisin gbogbo wa ti wa saye. Lehin na gbogbo nkan ma paari. Beena kilode teyin fe sukun? Ijiyan ti Krsna ti mu wa niyen. L'ona mejeji eyin o le sukun. Lehin na?

Pradyumna: ( Alaaye) " Beena toba tie jepe lati jiyan nikan awa gba imoye awon alainigbagbo, beena kosidi fun ekun sisun yi. awon ohun elo aye yi wa ninu ipo tio seri ki iseda yi to bere, afi emi wa nikan. Lati ipo tojepe awa o le foju ri won si ipo tojepe awa le foju ri won. Gege tojepe lati ofurufu, ategun le jade, l'ategun ina le jade, lati ina, omi le jade; Lat'omi, ile le jade. Lati ile yi orisiri nkan le jade...."

Prabhupada: Ilan iseda leleyi. Lati ofurufu, lehin na sanmo, lehin na ategun, lehin na omi, lehin na ile. Ilana iseda leleyi. Beeni.

Pradyumna: " Fun apeere ile oke giga ton wa lori ile. teyin ba wo lule, gbogbo loma pada si bose wa teletele, wan si wa ninu ipo yi. Ofin itoju agbara si daju, sugbon leyin igba die awon nkan ma farahan wansi paare. Iyato to wa niyen. Lehin na kini'di fun ekun sisun yi ninu ipo ton farahan ati ipo ti won o farahan? Bakana tabi ikeji, nini ipo tio se ri, awon nkan yi si wa nibe. Ni beere ati opin gbogbo awon nkan ma wa lori ipo tojepe awa o le foku ri, ninu ipo laarin nikan lawa le foju ri won, sugbon kosi iyato gidi kankan. t'awa ba si gba oro Veda bonse salaaye ninu Bhagavad-gita (antavanta ime dehāḥ) pe awon ara eda wanyi ma paari leyin asiko die (nityasyoktāḥ śarīriṇaḥ) sugbon tayeraye l'emi wa ma wa fun, Leyinna agbodo ranti pe bi aso ni ara eda yi seri. Nitorina kilode teyin sen sukun fun aso ton paaro? Ara eda yi koni igbese aye kankan ninu ibasepo pelu emi wa. Bi ala lose ri. A le laala pe awa fo lori sanma tabi pe awa sin joko lori oko-esin bi Oba, sugon ta ba ji awa ma riwipe awa o si lori ofurufu tabi oko-esin. Imoye Veda ti ko awon lati moni pa ara-eni ati wipe fun igba die lara eda yi ma wa fun. Nitorina teyan ba nigbagbo ninu emi tabi ko gbape emi kankan wa, kosidi fun lati sukun fun ipaari ara eda yi."