YO/Prabhupada 0635 - The Soul is there in Every Living Entities, even within the Ant



Lecture on BG 2.30 -- London, August 31, 1973

Olufokansi: Isotunmo: " O eyin aromodomo ti Bharata, eni towa ninu ara eda wa tayeraye, kode si besele fiku pa. Nitorina eyin ogbodo sukun fun eda kankan."

Prabhupāda: Dehī nityam avadhyo 'yaṁ dehe sarvasya bhārata. Dehe, ara eda nitumo dehe, ninu ara eda. Akole to bere, dehino 'smin yathā dehe kaumāraṁ yauvanaṁ jarā (BG 2.13). Deha, dehī. Eni toba ni ara eda nitumo Dehī. Gege bi guni. Āsthate in prata.(?) Guṇa, ninu, deha, ninu prata.(?) Dehin śabda. Beena oro ijinle ti dehin sabda ni dehi. Dehī nityam, tayeraye. L'ona to po. Krsna ti salaaye. Nityam, tayeraye. tiole baje, alaiyipada. Kole ni ibimo, kole ku, owo bosewa, nigbogbo'gba. Na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). Bayi na, otun sowipe nityam, tayeraye. Avadhya, koseni tole fiku pa. Ninu ara eda, owa nibe. Sugbon dehe sarvasya bhārata. Nkan tose pataki niyen. Konsepe ninu ara eda, emi wa nibe, kode si ninu awon eda iyoku. Iwa iranu niyen. Sarvasya. Ninu gbogbo ara eda. Ninu kokoro, ninu erin, ninu igi banyan nla tabi ninu kokoro. Sarvasya. Emi wa ninu won. Sugbon awon asiwere kan, wan sowipe kos'emi kankan. Otooro ko leleyi. Bawo lesele sowipe aawonn eranko o l'emi kankan? Gbogbo eyan. Nibi awon oro toje oro lat'olori Krsna: sarvasya. nibo'mi Kṛṣṇa sowipe, sarva-yoniṣu kaunteya sambhavanti mūrtayaḥ yāḥ: (BG 14.4) Ninu awon ara eda wanyi, ton po to 8,400,000 ara eda orisirisi, tāsāṁ mahad yonir brahma. Mahad yonir. Iseda yi ni orisun aye yi. Ahaṁ bīja-pradaḥ pitā: " Emi ni baba gbogob eda." Gege bi kole s'omo tio ni baba ati iya, beena Krsna ni baba gbogbo wa.

iseda aye yi ni mama wa, tabi iseda mimo. Awon iseda meji to wa niyen. Wanti salaye ninu ese-iwe meje. Iseda ile aye yi ati iseda mimo. Tabi iseda mimo tabi iseda kekere. Gege bi ara eda wa se ni awon apa kekere ati awon apa giga. Nkankana ni ara wa je. Sugbon awon apa orisirisi ara eda lowa. Awon imi ninu won kere si awon iyoku, awon imi si gaju awon iyoku lo. Awon owo meji. Ninu awon asa Veda, owo otun ni owo to gaju, owo osin lo kere. Teyin bafe fun enikan ni nkan, egbodo fun pel'owo otun. Teyin ba fun pel'owo osin, eebu niyen je. Agbodo lo awon owo mejeji na. Kilode ti owo se gaju ikeji lo..? Beena agodo gba nkan ti awon Veda ba so. Beena botilejepe awopn iseda mejeji, eyi toje mimo ati eyi toje t'aye yi, lati orisun, otito to gaju lonti wa.... Janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). Lat'ara re ni gbogbo nkan ti jade. Beena, iseda kekere ati iseda giga lo wa. Kini iyato laarin eyi to kere ju ati eyi to gaju? ninuu iseda kekere tabi iseda aye yi, imoye Oluwa o po rara. Awon tonwa ninu ipo rere, won ni imoye die nipa Oluwa. Awon ton wa ninu ipo ifekufe yi, won ni igba die; awon tonwa ninu ipo aimokan, kosi imoye Oluwa kankan ninu won. Kosi rara.