YO/Prabhupada 0639 - The Individual Soul is in Every Body and the Supersoul is the Real Proprietor



Lecture on BG 2.30 -- London, August 31, 1973

Beena ninu awon ipo aye kekere bi awon eranko, Krsna wa nibe. bose so, dehe sarvasya bharata (BG 2.30). Nibomi, Krsna sowipe dehi tabi ksetrsa-jna yi, toje onihun ara eda yi wa nibe, ksetra-jna imi tunwa, onihun imi. Krsna niyen. Kṣetra-jñaṁ cāpi māṁ viddhi sarva-kṣetreṣu bhārata (BG 13.3). Bi awon eda ototo wanyi se wa niju ara eda yi, emi to gaju yi, Krsna na wa nibe. Awon mejeji wa nibe. Awon mejeji wa nibe. Beena oun ni onihun gbogbo awon ara eda wanyi. gbogbo awon ara eda wanyi. Nigbami awon asiwere man fun Krsna l'eebu pe " Kilode tose ba awonn iyawo oniyawo jo?" Sugbon lootoro oun ni onihun. Dehe sarvasya bharata. Onihun konimi, Oun ni onihun. Beena ti onihun ba jo pelu awon oniranse re tabi awon olufokansi re, kilo buru nibe? Kilo buru nibe? Oun ni onihun. Onihun ko leje. Dehe sarvasya bharata. Eda onikaluku towa ninu ara eda ati emi to gaju, Emi togaju yi ni oniwun to daju. Krsna sowipe bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ sarva-loka-maheśvaram (BG 5.29). Maheśvaram, Oun ni oniwun to gaju Suhṛdaṁ sarva-bhūtānām. Oun l'ore gidi wa. Ti mo bani ololofe kan, nigbami a le s'ore, nigbami ale ma s'ore. Ore gidi tani ni Krsna. Suhṛdaṁ sarva-bhūtānām. Wanti salaaye wipe tasmād sarvāṇi bhūtāni. Kṛṣṇa ni ore gidi tani. Beena ti awon gopi bafe jo pel'ore gidi ton ni, kilo buru nibe? Kilo buru nibe? Sugbon awon asiwere wanyi, tio mo nipa Krsna, won rowipeiwa tio da niyen. Kosi nkan to buru nibe. Nkan to da niyen. Nkan to da. Oko to daju ni Krsna je. Nitorina lose fe iyawo 16,108. Kilode to se fe to 16,000? Toba fe iyawo to koja 16,000,000,000, kilo baje nibe? Nitoripe oun ni oko to daju. Sarva-loka-maheśvaram (BG 5.29).

Beena eni tio ba mo Krsna, asiwere wanyi, wan sowipe iwa Krsna o da, tabi o feran obirin, bayi bayi lo. Wansi gbadun re. Nitorina lonse kun awon iworan Krsna ppelu awon gopi. sugbon won o fe kun bosen pa Kamsa, bosen pa awon esu. Won o fe iru nkan bayi. Iwa sahajiya niyen, fun isekuse, fun ise isekuse tonfe se, wonfe lo Krsna fi seto na. " Krsna ti se bayi bayi." " Oni'wa buruku ni Krsna. Beena oni'wa buruku l'awa na. Olufokansi pataki ti Krsna niwa, nitoripe awa ni iwa tio da." Nkan ton sele niyen. Nitorina, lati ni oye Krsna,m oye ka lo ogbo ori wa dada. Ogbon ori to da. Bahūnāṁ janmanām ante jñānavān (BG 7.19). Awon ologbon tipo kini nitumo Jñānavān. Māṁ prapadyate. O ni oye nipa Krsna. Vāsudevaḥ sarvam iti sa mahātmā sudurlabhaḥ. Iru ogbon mahatma... Ele ri awon mahatma, ton paaro aso wan nikan, laini imoye Krsna, tonpe ara won ni Krsna tab'Olorun. E funwon nipa loju won. Krsna yato si awon oniranu wanyi. sugon teyin ba ni oye nipa Krsna, teyin ba ni orire yi - ei rūpe brahmāṇḍa bhramite kona bhāgyavān jīva (CC Madhya 19.151). Awon eyan ton sorire nikan lonle ni oye nipa Krsna, eni ti Krsna je.