YO/Prabhupada 0645 - One Who Has Realized Krishna, He is Always Living in Vrndavana



Lecture on BG 6.1 -- Los Angeles, February 13, 1969

Prabhupada: O da, kini ibere toni?

Olufokansi: Se Ksirodakasayi wa ninu awon eda tio l'emi, bi awon okuta?

Prabhupada: Hm?

Olufokansi: Se Ksirodakasayi Visnu wa ninu awon eda tio l'emi?

Prabhupada: Beeni, beeni, ninu awon atomu gan.

Olufokansi: Ninu irisi pel'apa meerin..?

Prabhupada: Oh beeni.

Olofokansi: Kini..?

Prabhupada: Ibikibi toba wa, owa ninu awon oun elo re. Aṇor aṇīyān mahato mahīyān. O tobi ju oun to tobiju, osi kere ju oun to kere ju. Visnu niyen. Aṇḍāntara-stha-paramāṇu-cayāntara-stham (BS 5.35). Atoomu nitumo Paramāṇu. Eyin o le ri awon atomu gan, seri bose kere to. O wa ninu atomu. Owa nibikibi.

Tamal Krsna: Prabhupada, e sofun wa pe, ibikibi ti Krsna ba wa pe Vrndavana nibe na. Mosin ronu pe, ti Krsna ba wa ninu okan wa, se iyen wipe ninu okan wa .....

Prabhupada: Beeni. Eni toba ti jeeri, owa ni Vrindavan nibiki toba wa. Awon emi giga wa ni Vrndavana nibikibi. Caitanya Mahaprabhu ti sowipe. Enito bati jeerisi Krsna, lehin nao wa ni Vrndavan nigbogbo'gba. Gege bi Krsna tabi Visnu towa ninu okan gbogbo awon eyan, sugbon owa ninu okan aja na. Seyen wipe oti ni iwa aja? O wa ni Vaikuntha. Botilejepe o wa ninu okan aja, sugbon osi wa ni Vaikuntha. Beena awon olufokansi le gbe nibikan to jina si Vrndavana, sugbon o wa ni Vrndavana. Otooro niyen. Beeni. ( Opin)