YO/Prabhupada 0646 - Yoga System is Not that You Go On Doing All Nonsense



Lecture on BG 6.2-5 -- Los Angeles, February 14, 1969

Prabhupada: talon kawe?

Olufokansi: Ese iwe keji. " Nkankana ni yoga pelu ikorasi awon nkan aye yi, tabi asepo pelu Eledumara, koseni tole di yogi afi toba yoo ife okan lati gbadu iye ara re kuro l'okan re. (BG 6.2)."

Prabhupada: Koko oro adase yoga leleyi. Lati parapo nitumo Yoga. Nisin ninu ipo aye wa, botilejepe aw je nkankana pelu Eledumare, sugbon awa si yato. Apeere kanna. Nkankana ni ekana yin je pel'ara yin, sugbon teyin ba ge kuro, ko wulo mo. Sugbon toba si wa paapo pel'ara yin, aimoye dollar ti iyi re je. teyin ba ni aisan laara ele f'owo fi yonju e. Beena, lasiko tawayi, nini ipo ile aye yi, awa ti yo ara kuro s'Olorun. Nitorin l'awa o se fe soro nipa Olorun, lati ni oye nipa Olorun, ibasepo tani pel'Olorun. Awa si rowipe ilokulo asiko wa leleyio je. Ninu ipade yi, gbogbo wa lamo, ninu ile-ijosin yi, imoye Krsna, awa sin soro nipa Oluwa. Tabi ile adura. Awon eyan o si nife fun awon nkan wanyi. Won rowipe ere idaraya loje, pel'oruko ilosiwaju mimo, bibeko ilokulo asiko loje. Wan ma jeere gan tonba lo asiko yi fi p'owo. tabi kon fi gbadun ninu ile ounje, igbadun iye ara. Itumo igbadun iye ara ni iyipo lat'Oluwa Awon eyan ton feran igbadun iye ara, awon eyan wanyi o le sise ninu ilana yoga. Konsepe eyin ba se iranu yin tan kesi joko pe efe sasaro, Yoga ko niyen. Iranu leleyi, kosi itumo kankan. Lati ni idari lori iye ara wa nitumo alakoko fun Yoga, yama, niyama. Ipo mejo lowa ninu ise adase yoga. Yama, niyama, āsana, dhyāna, dhāraṇā, prāṇāyāma, pratyāhāra, samādhi. Beena nibere ninu apa iwe yi, Oluwa Krsna ma kowa nkan ti yoga je. Nitorina ni'bere Krsna sowipe koseni tole di yogi, afi toba fi gbogbo ife okan fun igbadun iye ara re sile. Beena enikeni toba fe gbadun ara re, oniranu loje. Yogi ko loje, Kole di yogi. Kole si imo ako ati abo kankan ninu ilana Yoga. ilana yoga nkyen. Koseni tole di yogi toba n'se ni imo ako ati abo. Awon yogi eke wanyi tonba wa si ilu yin wan sowipe, " Beeni, ese bose wunyin. ke sasaro, ma funyin ni mantra." Iranu ni gbogbo e. Koko oro to daju leleyi pe, koseni tole di yogi afi toba fi awon ife okan toni fun igbadun iye ara re. Ipo kini niyen. tesiwaju.

Olufokansi: Ese iwe keta. " fun eni tosese bere ninu ilana ipo mejo ti yoga, ise l'ona toye ko gba. eni toti bosinu ipo yoga, ipaari si gbogbo ise l'ona toye ko gba. (BG 6.3)."

Prabhupada: Beeni. Awon ipo mejeeji leleyi. Eni ton sewaadi ninu yoga lati de ipo to gaju, at'eni toti der ipo to gaju yi. Beena, botilejepe onitoun koi ti de ipo to gaju yi, ton gbiyanju, lasiko yi ise toye ko se po gan. Ilana asana, yama, niyama. Beena ninu orile-ede yin awon egbe yoga po gan. Wan fi awon ilana yoga wanyi fihan, Besele joko, ati orisirisi igbera. Oma ranwon lowo. Sugbon nkan toma mu won wa sori ipo gidi niyen. Ona lasdan niyen je. Ilana yoga gidi yato si gbogbo awon ere ara eda wanyi. Ipo meji lowa. Ikan fe de ipo to gaju yi, ikeji ti de ipo to gaju na.