YO/Prabhupada 0654 - You Cannot See God by Your Endeavor Because Your Senses are All Nonsense



Lecture on BG 6.6-12 -- Los Angeles, February 15, 1969

Gege bi Bhagavad-gītā se sowipe:

patraṁ puṣpaṁ phalaṁ toyaṁ
yo me bhaktyā prayacchati
tad ahaṁ bhakty-upahṛtam
aśnāmi prayatātmanaḥ
(BG 9.26)

"teyan ba funmi ni odod, eso, efo, wara, pelu ife okan, M'agba masi je." Nisin bawo losen jeun, eyin o le foju ri nisin - sugon On jeun. Awa sin jeerisi lojojumo. Awa sin fun Krsna ni nkan gege boseye, eyin ma riwipe itowo ounje na ma yato lesekese. Idaniloju to wa niyen. On jeun, sugbon nitoripe ebi o pa, Ko jeun b'awa sen jeun. Gege bi tin ba fun yin lonje, e ma paari e. Sugobn ebi o pa Olorun, sugbon asi jeun. A jeun sugbon asi fisile bose wa. Pūrṇasya pūrṇam ādāya pūrṇam evāvaśiṣyate (Śrī Īśopaniṣad, Invocation). Olorun wa ni pipe, ole je ounje teba fun, sugbon asi wa bose wa. Ole jeun pel'oju. Wanti salaaye ninu Brahma-saṁhitā: aṅgāni yasya sakalendriya-vṛttimanti. Gbogbo apa ara Olorun lese gbogbo nkan ti awon apa iyoku lese. Gege b'eyin selse riran pel'oju, sugbon eyin o le jeun pel'oju. Sugbon Olorun, toba kan wo ounje teyin muwa fun, jijeun re niyen. Beena awon nkan wanyi ko leyewa nisin. Nitorina ni Padma Purana se sowipe, Afi teyan ba ti yasi mimo ninu ise ifarafun Oluwa, lehin na ni onitoun le mo nipa oruko, irisi, amuye ati akoko idaraya t'Oluwa. Kole ye yin pel'agbara yin nikan, sugbon Oluwa le fi han yin. gege bi teyin bafe ri orun nisin. Okunkun ti wa nisin. Teyin ba sowipe, " Oh wa moni atupa to da, mofe fi ina orun fi han e " Eyin o le fihan. Sugbon t'orun ba jadu laaro, ele ri. Beena eyin o le foju ri Oluwa pelu agbara yin nitoripe iranu nigbogbo iye ara yin je. Egbodo ya iye ara yin si mimo egbodo duru fun asiko yi nigbati inu Olorun ba dun asi f'arare han niwaju yin. Bose wa niyen. Eyin o le baja." Oh Olorun mi, Krsna mi, e dakun e wa. Mofe ri yin." Rara, iranse yin ko l'Olorun je, oniranse fun yin. beena ti inu re ba dun, asi farahan, ema ri. Beena ilana wa ni basele fun ni itelorun kobale farahan simi. Ilana to daju niyen. Nitorina lonse sewaadi lori Olorun iranu. Nitoripe kosi bonsele ri Olorun s'oju, enikeni le jade ko sowipe " Olorun nimi," Awon eyan asi gba. Sugbon awon eyan wanyi o mo eni t'Olorun je. Enikan le sowipe " Mon sewaadi lori otito," Sugbon eyin gbodo mo nkan ti otito yi je, Bibeko bawo lesele sewaadi fun otito yi? kasowipe eyin fe ra wura. Eyin gbodo mo nipa bi wura se ri. Bibeko awon eyan ma tan yin je. Beena wanti tan awon eyan wanyi je, ton gba awon oniranu wanyi b'Olorun. Nitoripe won o mo eni t'Olorun je. Enikeni lewa, " Oh, Olorun nimi" Asiwere ni ounitouin je, okurin toba sowipe " Olorun nimi," aasiwere loje. Awujo awon asiwere, wanswi gba were kan b'Olorun. Olorun o ri bee. Eyan gbodo ni amuye lati ri Olorun, lati ni oye nipa Olorun. Imoye Krsna niyen. Sevonmukhe hi jihvādau svayam eva sphuraty adaḥ [Bhakti-rasāmṛta-sindhu 1.2.234]. teyin ba sise fun Olorun, lehin na eyin ma ni amuye lati ri Olorun. Bibeko kolese se. Tesiwaju.