YO/Prabhupada 0669 - Fix Up The Mind Means To Keep Your Mind In Krishna



Lecture on BG 6.16-24 -- Los Angeles, February 17, 1969

awon olufakansin: ese nombar merindinlogun: eyon ti oba ni ofin ihuwasi ninu ji jeoun ree, ninu sisun ree ati ere idaraya ole petu gbogbo isoro ti ile aye, ti won ba didase eto yoga (BG 6.17)."

prabhupada: beeni, iwo ni lati jiroro ni.....ko si oro ibeere lati lo si kilasi ekor yoga oni lati san rupee marun tabi dollar marun, lati dinku ora ti o wa lara ree, ati lati jeki ara ree waa ni ilera oni lati jiroro. jiroro yi je pe. je oun ti ofe ati sun orun ti ofe ilera re yio dara, sugbon ko se pataki ti aba jiroro yi gbogbo nkan ma dara awon

olufankansin: ẹsẹ nọmba mejidilogun:nigbati yogi,pelu adase yoga ti eyon ba ni orisirisi eko ati imor, oye re yio wa pipe eyon ti ko nii iferaan fun owun ile aye iyonda,owun ni o mo ituumo yoga (BG 6.18)."

prabhupada. beeni lati fi okan wa si ona kan owun ni akoye yoga lati fi okan bale.. bi iwo sheee le shee niyen? ti oba ni ile ise o le fi okan re baale, ko shen nse fun apeere bhagavad-gita ti iwo ba ka ni ojojumo, fun wakati merin, ko ni sun eee sugbon ti oba mu iwe miiran, ti oba ka fun wakati kan yio sun ee ikewe hare krsna yi, ti oba kewe fun gbogbo ojo ale tabi aro,ati ti oba njo ko ni sun ee sugbon ti oba kewe orukor miiran, lehin wakati kan o ti sun ee o je ipanilara, see orii nitorina, fi okan si otumosiwipe je ki okan re wa ni odor olorun(krsna) ni igba gbogbo, lehina gbogbo yoga ba pari i wo je yogi ti o wa ni pipe, o ni lati shee nkankan,shaa fi okan re si ona kan nikan Sa vai manaḥ kṛṣṇa-padāravindayor vacāṁsi vaikuṇṭha (SB 9.4.18) - ti oba soroo, soroo nipa krsna, ti oba jeon, je ounje krsna ti oba ronu, ronu nipa krsna, ti oba se ise, se ise fun krsna ni ona yi, ikosara yoga yi yio wa ni pipe kon nse bibetiko. ayi ni o je pipe yoga, ti ko ni akonjuwa isada ti ile aye ti oba ronu fun krsna, ibo wani ironu fun aree aye ti waa opari,gbogbo ironu fun ere aye iyonda pari, iwo ni lati tiraka fun loju lasan oh, emi ko ni ri omo obinrin ti o rewa, e mi yio di oju mi,eyi iwo o lee sheee sugbon ti oba fi okan re si aiiji krsna, iwo njo pelu omo obirin ti o rewa benii ko si wahala, nitoripe iwo nse bi egbon si aburo, ko si ibeere iwu nibe eyi je pipe iwulo sise yoga, ni oju lasan iwo ko le see sugbon ninu aiiji krsna gbogbo owun pipe aye wa nibe gbiyanju lati mor oye yi gbogbo pipee nitoripe eyi ni ni ona ti emi ona ti emi wa ni ayeraye,o kun fun alaafia ati oye kosi iseye-meji, benii losiwaju