YO/Prabhupada 0708 - The Difference Between the Life of the Fish and My Life



Lecture on SB 3.26.32 -- Bombay, January 9, 1975

Nitoripe moje emi , mio ni nkankan se mo pelu ile aye yi. Asaṅgo 'yaṁ puruṣaḥ. Emi wa o ni nkankan se pelu aye yi. Sugbon nitoripe oti ni asepo pelu aye yi, lorisirisi ona, ara wa nisin... ti somo. gege bi eja sen somo ohun ipeja, beena, awon eda aye yi, ile aye yi ti di wa mu ninu awon ohun ile aye yi. Ipo to le gan lawa. gege bi eja ton mu ninu ohun ipeja, t'apeja, tabi maya, Beena, ile aye yi ti mu wa. Prakṛteḥ kriyamāṇāni guṇaiḥ karmāṇi sarva... (BG 3.27). Nitoripe awa ti ni nkan se pelu ara yi, oti diwa mu. Gege bi eja ton mu, wanti di awa na mu. Bi omi okun nla ni ile aye yi je, bhavarnava. Omi okun nitumo Arnava, iyika ninu ibimo ati'ku nitumo bhava. nkan ton pe ni bhavarnava niyen. Anādi karama-phale, paḍi' bhavārṇava-jale. Anādi karma-phale: Ki iseda yi to da, moti ni irisi gbogbo nkan timo se seyin, l'ona kan tabi keji moti bosinu omi okun bhavarana, iyika ibimo ati'ku." Beena bi apeja sen mu eja, tojepe eja na n'ja lati wa laaye, lati jade lowo apeja.. kole l'aalafia. Eyin na mariwipe lesekese ton bamu, "Fut! Fut! Fut! Fut! Fut!" Afe jade. Itiraka wa na niyen, basele jade. Sugobn awa o mo.

Afi pelu ore-ofe Krsna kosi basele jade kuru ninu ara eda yi. Oun lole se ounkoun. O le yowa kuru lesekese ninu idimu yi. Bibeko bawo lose je Eledumare? Mio le jade. Eja na o le jade.. Ti apeja bafe, o le mu eja na ko ju s'omi. Asi wa laaaye. Beena, taba teriba fun Krsna, o le mu wa jade lesekese. O si sowipe, ahaṁ tvāṁ sarva-pāpebhyo mokṣayiṣyāmi mā śucaḥ (BG 18.66). Teyin ba teriba. Ti apeja yi ban ri "Fut! Fut! Fut!" sugbon t'eja na ba teriba.. O fe teriba sugbon ko mo bosele so. Nitorina asi wa ninu idimu apeja na. Sugbon t'apeja yi ba fe, o le mu ko ju sinu omi Beena, taba teriba fun Krsna.. Lati teriba nidi fn ile aye eda. awon eda imi - kosi bonsele se, sugbon molese. Iyato laarin aye mi ati t'eja niyen. Eja towa ninu idimu apeja y,kol'agbara kankan. Oti te.