YO/Prabhupada 0711 - Kindly What You Have Begun, Do Not Break It - Continue It Very Jubilantly



Speech Excerpt -- Mayapur, January 15, 1976

Prabhupāda: Igbadub to gaju ninu nakn yi ni pe anfaani Bhaktivinoda Thakura pe awon omo ilu Europu, America ati India wan le wa papo, kon jo dada at kon korin " Gaura Hari."

Beena ile-ajosin yi ,ile-ajosin Māyāpur Chandrodaya wa fun akojopo mimo awon Orile-ede. Nkan ti Akojopo orilede lasan kose, awa ma se nibi, pelu ilana ti Śrī Caitanya Mahāprabhu ti fun wa

pṛthivīte āche yata nagarādi grāma
sarvatra pracāra haibe mora nāma
(CB Antya-khaṇḍa 4.126)

Beena lati orisirisi ilu ni gbogbo yin ti wa, esin gbe papo ninu ile-ajosin yi. E ko awon omo-okurin kekere wanyi. Inu mi si dun gan lati ri awon omo kekere wanyi lati gbogbo awon ilu wanyi ati India, Bengali papo, tonsi gbagbe eto iru ara wo loni. Ilosiwaju to gaju ninu egbe wa leleyi, pe gbogbo wa le gbagbe eto ara wa. Koseni ton ronu pe " omo ilu Europu nimi," " omo ile America nimi, " "Omi ilu India nimi," "musluman nimi," " Kristeni nimi," wanti gbagbe gbogbo nkan bayi, wan sin korin Hare Krsna mantra taya taya. Beena E dakun nkan teti bere yi, eme baaje. E tesiwaju bayi. Beena Caitanya Mahāprabhu, Olori Māyāpur, inu re asi dun siyin, Leyin na ema pada lo s'odo metalokan.

Ese pupo. (Ipari)