YO/Prabhupada 0714 - No Matter What is the Profit, I Shall Speak for Krishna



Lecture on SB 1.16.24 -- Hawaii, January 20, 1974

Kala, akoko, se pataki gan. Akoko.. Pelu asiko ele se gbogbo nkan, pel'asiko na inu yi le dun si, pel'asiko na ibanuje le mu yin, Asiko le funwa, Krsna de l'akoko yi, kāla-rūpeṇa Eyin ma ri ninu Bhagavad-gita ninu Apa iwe mokanla.. Moti gbagbe pe... "Talo je?" Eda ti Arjuna ri, virad-rupa, Arjuna sowipe, " Taloje Oga?" Gege na o sowipe " kala-rupa nimi, pelu irisi akoko. moti wa pa gbogbo yin." Beena ise wa niwpe ninu ile aye yi agbudo lo fun imoye Krsna. Awa o gbodo sise imi. Egbe Caitanaya Mahaprabhu niyen. Kole rara. Kofi be le. Kīrtanīyaḥ sadā hariḥ (CC Adi 17.31). Sugon o le gan. O le gna lati korin Hare Krsna mantra fun wakati merin lelogun. Awon tiko o lara, wan ma ya were ton ba korin bayi. Kole se( ko daju). Eyin o le farawe Haridasa Thakura, pe " Nisin mofe losi bi t'awon eyna osi kin korin Hare Krsna." Kolese se, Sa. Eyan gbodo ni ilosiwaju dada lati fokan si orin kiko Hare Krsna mantra yi. Ko rorun. Nitorina fu awon ton sese bere, ani orisirisi nkna ton lese. Teyin ba sese bere ema farawe awon ton ti ni ilosiwaju gan, koni da rara. tawa baje awon ton sese bere, agbodo sise gan. Krsna si ni ona orisirisi lati funwa ni'se se. Ele sise fun Krsna l'ona orisirisi. Karmaṇā manasā vācā etāvaj janma-sāphalyaṁ dehinām iha dehiṣu. Karmaṇā manasā vācā śreya-ācaraṇaṁ sadā. Karmaṇā manasā, ona meta lowa: pelunise, karmana; pelu ironu, manasa, karmana manasa vaca ati pel'oro wa. a le se awon nkan wanyi. Karmana mansa vaca. itumo tridaṇḍa-sannyāsa.. danda merin lowa. Ikan ninu awon danda leyan na. meta to ku ni ara eyan na, okan re ati oro ton o. Itumo danda yi ni wipe, boya eyin o mo, Egbiyanju lati mo... Beena karmana, itumo danda yi "Moti jerisi pe mofe sise, pelu gbogbo nkan ti mo bani." Awon ohun ini mi. mole sise pelu ara mi, pelu okan mi, pelu awon oro tin ba so. itumo tridaṇḍa-sannyāsa ni eni to ti fun igbese aye re, ise re, ara re, ati oro enu re. tridaṇḍa-sannyāsa niyen Enikeni toti fun okan re, ara re at'oror enu re fun ise Olorun lon pe ni sannyasi. Pe a wo aso imi konitumo sannyasi, tan si ronu nkan imi. Rara. teyan ba lo okan re, pelu ara re,at'oro enu re, sa sannyasi.

Anāśritaḥ karma-phalaṁ kāryaṁ karma karoti yaḥ, sa sannyāsī (BG 6.1), Kṛṣṇa says. Tani sannyasi? Anāśritaḥ karma-phalam. "Mofe soro nipa Krsna." Ijeere wo ni mofe ni? Boya ijeere wa tabi tosi, mofe soro fun Krsna. Otan" Sa sannyāsī, Kṛṣṇa sowipe. "Ise mi niyen, karyam." Ise nitumo Karyam. Ise mi nilati soro nipa Krsna nikan. Otan. Mio ni soro nipa nkan imi. Sannyasi. Anāśritaḥ karma....teyin ba pe adajo ko soro fun yin ninu ile ejo, " Lesekese loma sowipe, ema dollar egberun meji wa." Nkan to ma berre niyen. Sugbon sannyasi, a soro fun wakati merin fun Krsna, lai bere nkankan. Sannyasi niyen. Wakati merin nnu ise Krsna - sanyassi niyen. Wakati merin ton ronu Krsna - Sannyasi loje. sannyasi niyen. Koni ise imi. Anāśritaḥ karma-phalaṁ kāryaṁ karma... gbogbo eyan lon sise fun ijeere ara re, " aduru owo wo nimo fe pa? Aduro okiki at'oruko wo nimo fe ni?" Fun igbadun ara re. Ile aye yi niyen. Nkan aye yi niyen. lesekese teyan ban sise fun nkan ara re, nkan aye yi niyen. lesekese teyan ba sise fun Krsna, nkan mimo niyen. Otan. Iyato laarin nkan aye yi ati nkan mimo niyen.