YO/Prabhupada 0722 - Don't Be Lazy. Always Remain Engaged



Arrival Lecture -- Mexico, February 11, 1975, (With Spanish Translator)

Inu mi dun lati ri gbogbo yin, awon eyan tio yato si Krsna. Eti wa lati ni oye nipa imoye Krsna. E foju si awon ofin wa, lehin na ile aye yin ma ni aseyori. Lati di mimo lofin wa. gege b'okurin t'ara re o ba ya, ogbodo di mimo pelu awon ofin, ounje, at'ogun, beena, awa na sini asian ara yi ton bowa, aaami aisan yi ni ibimo, iku, ojo arugbo ati aisan. enito ba fe jade ninu idimu aye yi ko ni gbala lati ibimo, iku, ojo arugbo ati aisan, ogbudo gba imoye Krsna yi. O rorun gan. Teyin ba mo, teyin o ba keeko, teyin o ba ni ohun elo kankan, ekorin Hare Krsna maha-mantra yi. teyin ba l'ogbon, teyn baje alakowe, ele ka awon iwe wa, ton pe aadota nisin. Awon iwe yi to marundinloogorin pelu ese iwe ogorun merin, lati le fun awon alakowe, onisayensi, ati akeko nipa nkan ti imoye Krsna yi je. O wa ninu ede geesi ati awon ede europu na. E mu ni pataki. pelu adura si irisi Olorun, e keeko awon iwe wanyi fun wakati maarun . gege bu awon ile-iwe, lojojumo lon kekko, fun iseju maarundinlaadota, fun iseju merin si mewa wan simi, wan tun bere, bayi Asi ni nkan to po lati ko. teba fe ka gbogbo awon iwe wanyi, ato odun marun lelogun lati paari won. Gbogbo yin si wa lasiko odo yi, edakun e ka awon iwe yi, ninu orin kiko, ninu adura si irisi Olorun, ninu iwaasu, iwe tita. E ma yoole. E wa nkan se nigbogbo igba. Imoye Krsna niyen.

Krsna sowipe ninu Bhagavad-gita,

māṁ hi pārtha vyapāśritya
ye 'pi syuḥ pāpa-yonayaḥ
striyaḥ vaiśyās tathā śūdrās
te 'pi yānti parāṁ gatim
(BG 9.32)

Kosejo isasoto pe " Ema jek'okurin yi wa; ema jeki'obirin yi wa." rara. Krsna sowipe " enikeni" - striyaḥ vaiśyās tathā śūdrās. Enikeni toba gba imoye Krsna yi, oma nigbala lati idimu ile aye yi asi pada si odo Metalokan, si ile. Emu egbe yi ni pataki, ke tele aeon ofin na, ema jeran, ema se imo ako ati abo lai se igbeyawo, ema moti, ema ta tete ati ke korin oruko Olorun fun igba merilelogun.