YO/Prabhupada 0726 - Rise Early in the Morning and Chant Hare Krishna



750304 - Lecture CC Adi 01.15 - Dallas

Nārada Muni ti funwa nimoran ninu Srīmad-Bhāgavatam, wipe, Eyin tini ile aye eda yi. Nisin eyin o ni lati wa nkan tema je, tabi ibi teba sun nibo ni igbadun imo ako ati abo yin wa, nibo ni igbeja yi wa. Isoro yin ko niyen. Egbodo gbiyanju fun nkan, tole fun yin ni igbala lowo awon nkan aye yi." Imoran to fun wa niyen. Laaro yi awa ri wipe, iru orile ede nla bayi, ounje ni isoro ton ni. Laaro kutu ni wakati mefa awon eyan lo sibise. Kilode ton lo sibi ise. Kilode? Lati wa nkan igbadun aye yi.

iru awujo wo leleyi? Ninu awon iwe Veda eyan gbodo ji laaro kutu lati gbadura orin Hare Krsna, kosi se mangala aratrika, ko gbadura si irisi Olorun. Ise aaro wa niyen. Sugbon awon orile-ede to lowo ju laaye yi, wan losibi ise fun ounje. Se ilosiwaju gidi niyen? wan sise lataaro d'aale. Nibi nikan ko, ibikibi, lati le ri ounje je, wan lo sibi to jina lati le. Ni orile ede India, nkankana lon sele - ni Bombay, wan wa lati ibi to jina gan, ninu oko Wanti salaaye ni Srimad-Bhagavatam pe awon eda ma sise gan lasiko ti kali ba fe tan.... Wan si be eranko, sugbon wan gbodo sise bi eranko lati ri nkan je. ilosiwaj wan leleyi. Awon ounje gidid bi eso, efo, wara, iresi, suga, awon nkan wanyi oni si mo - gbogbo e loma tan. Iru ilosiwaju ta ma ni leleyi. Moti ri fun ara mi. molo si Moscow, awa o le gbe nibe Kosi iresi Ko s'efo, kos'eso, eso toti baje lowa fun eyan bi t'awa awa o le gbe nibe.

Wara at'eran po nibe na ele ri to po gan. Ile aye eda.. Kaviraj Gosvami ti salaaye, mat-sarvasva-padāmbhojau rādhā-madana-mohanau. nkan ohun elo tani ni ese krsan ati ti Radharani Madana-mohana. Kṛṣṇa si lewa gan to jepe o lewa ju orisa ife Madana-mohana. Madana itumo re ni orisa ife. Orisa ife yi ni eni to lewa ju ninu agbaye yi, sugbon Krsna si lewa ju lo. Kandarpa-koṭi-kamanīya-viśeṣa-śobham (Bs. 5.30). wanti salaaye ninu awon sastra. nigbat Krsna gan wa laayeyi awon eyan jerisi pelu sastra na pe Krsna lewa gan tojepe awo gopi si feran re gan. Awon gopi ni awon obirin ton lewa ju, wansi feran Krsna gan. Sele ronu bi Krsna se lewa to. Awon gopi nikan ko awon iyawo 16, 108 toni. nitorina l'oruko re se je Krsna. Gbogbo eyan lo feran re. Jayatam suratau paṅgor mama. kilode ti awa o le ni ifarasi? Ipo Krsna niyen.