YO/Prabhupada 0731 - Bhagavata-dharma is not Meant for Persons who are Envious



Departure Lecture -- London, March 12, 1975

fun awon olufokansi, teyan ba ko iwe dada pelu oro to lewa gan Tad-vāg-visargo, na tad vacaś citra-padam, prlu awon oro to lewa gan, na tad vacaś citra-padaṁ harer yaśo na pragṛṇīta karhicit, sugobn ti ko daruko Krsna tabi ogo re... gege bi ilu geesi teni awo iwe iroyin, to tobi gan sugbon kosi nkankan nipa Krsna ninu re. fun awon olufokansi, iranu leleyi. Tad vāyasaṁ tīrtham. Gege bi vayasam, awo eye kuroo. Nibo ni awon eye kuroo man peejo? Nibi ti awon iranu wa. Iwa iru eye yi leleyi. Ibi ton ju awon nkan idoti si, lon pee jo. Eye imi ton pe ni siwani kole losi. Awon eye siwani ma pe jo nibi t'omi to mo wa, idodo, ati awon eye ton korin. ibi ton pe jo niyen. Orisirisi eranko lowa, " Awon eye pelu iye kanna lon paapo." Ibi kuroo ma loawon siwani o ni lo sibe. Ibi ti awon siwani ma lo, awon kuroo o ni lo. Beena egbe imoye Krsna yi fun awon siwani lo wa fun, fun awon Kuroo ko. Egbiyanju lati je siwani, rāja-haṁsa, tabi paramahaṁsa. Siwani nitumo Haṁsa. Ema losi odo awon kuroo, bobatiejepe odo wa kere, ile oti, ile-ijo, .. Nipataki ni awon ilu geesi ti awon eyan feran awon ibi bayi, ema gbe ile aye yin bi kuroo. E di siwani ke gba ilana yi, ke korin ke gbo nipa Krsna. Ilana to wa niyen, lati di paramahamsa. Dharma-projjhita-kaitava atra nirmatsarāṇām. Dharma-projjhita-kaitava atra paramo nirmatsarāṇām (SB 1.1.2). Bhāgavata-dharma, imoye Krsna yi, wa fun paramo nirmatsarāṇām. Matsara, matsarata.Itara nitumo Matsara Moni itara si yin, eyin na ni itara si mi.Ile aye yi niyen. Gegebi awon eyan ninu adugbo wayi , wan po toni itara, wan ko fejo sun wa. Ati jerisi gan. Beena Bhāgavata-dharma wa fun paramo nirmatsarāṇām. Eni tio fe ki awon elomi ni ilosiwaju lonpe ni Matsarata. Nkan ton pe ni Matsarata. Iwa gbogbo eyan niyen. Gbogbo eyan fe ni ilosiwaju ju awon iyoku lo. Awon aladugbo wa ni itara siwa: "Oh Okurin yi ti ni aseyori. Mi o de ni>" Bobatie je aburo re, tabi omo re.. iwa eda niyen Beena Bhagavata-dharma yi o wa fun iru awon eyan bayi, ton ni itara. fun awon paramo nirmatsarāṇām lowa fun, ton ti fi iwa itara yi sile. Bawo lasele se? Ele se teyin ba ti ko nipa ife si Krsna. Lehin na le lese. Lehin na ele riwipe nkankan ni gbogbo wa pelu Krsna. Beena o jiya nitoripe koni imoye Krsna. Eje ki soro nipa Krsna Ejekin fun ni iwe nipa Krsna, beena nijokan a ni imoye Krsna inu re asi dun." śravaṇaṁ kīrtanaṁ - ilana smaraṇam Awa na gbodo lati awon olori nigbogbo igba, kasi ma korin yi lo. Otan Lehin na inu gbogbo eyan ma dun. Bibeko, akojopo awon eye kuroo ninu ile-idoti kole tan, koseni ti ibu re madun bayi.

Ese pupo.

Olufokansi: Ogo ni fun yi Srila Prabhupada! (ipari)